Saad Al-Salim Al-Sabah
Sheikh Saad Al-Abdullah Al-Salim Al-Sabah, KCMG (Hon) (Lárúbáwá: سعد العبد الله السالم الصباح Saʿd al-ʿAbd Allāh as-Sālim as-Sabāh) (1930 – 13 May 2008) ló jẹ́ Ẹ́mírì ilẹ̀ Kùwéìtì àti Aláṣe Ológun ilẹ̀ Kùwéìtì fún ìgbà ṣókí ọjọ́ mẹ́sàn (láti 15 dé 24 January 2006), nígbà tó rọ́pò Sheikh Jaber. Sheikh Saad jẹ́ ọ̀gá aláṣe ní ilé-iṣẹ́ Ológun ilẹ̀ Kùwéìtì, ó tún jẹ́ alákòóo Ilé-iṣẹ́ Àkóso Ọ̀rọ̀ Abẹ́lé títí di February 16 1978.since 1964.[2]
Saad Al-Abdullah Al-Salem Al-Sabah | |
---|---|
Sheikh Saad in 1991 | |
Reign | 15–24 January 2006 |
Predecessor | Jaber Al-Ahmad Al-Jaber Al-Sabah |
Successor | Sabah IV Al-Ahmad Al-Jaber Al-Sabah |
Spouse | Sheikha Latifa bint Fahad Al-Sabah |
House | House of Al Sabah |
Father | Sheikh Abdullah Al-Salim Al-Sabah |
Mother | Jameela (an Ethiopian)[1] |
Born | 1930 Kuwait |
Died | 13 May 2008 Kuwait | (ọmọ ọdún 77–78)
Religion | Islam |