Kùwéìtì

(Àtúnjúwe láti Kuwait)

Orílẹ̀-èdè Kùwéìtì (Lárúbáwá: دولة الكويت‎, pronounced [dawlat alkuwayt]) je Ile-Emiri Arabu aladani to ni bode mo Saudi Arabia ni guusu ati Irak ni ariwa ati iwoorun. Ijinna to pojulo lati ariwa de guusu je 200 km (120 mi) ati lati ilaoorun de iwoorun je 170 km (120 mi). Iposieniyan re je 2.889 legbegberun ati agbegbe 18,098 km².

Orílẹ́-ẹ̀dẹ̀ Kùwéìtì
State of Kuwait دولة الكويت
Dawlat al-Kuwayt
Àsìá
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèAl-Nasheed Al-Watani
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Kuwait City
29°22′N 47°58′E / 29.367°N 47.967°E / 29.367; 47.967
Èdè àlòṣiṣẹ́ Arabic
Orúkọ aráàlú Ará Kuwait
Ìjọba Constitutional hereditary emirate[1]
 -  Emir Sabah Al-Ahmad Al-Jaber Al-Sabah
 -  Prime Minister Nasser Mohammed Al-Ahmed Al-Sabah
Establishement
 -  First Settlement 1613 
 -  Bani Utbah tribe foundation 1705 
 -  Anglo-Ottoman Convention 1913 
 -  Independence 19 June 1961 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 18,098 km2 (157th)
6,880 sq mi 
 -  Omi (%) negligible
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 2,889,042[2] (137th)
 -   census 2,889,042 (20.1% are kuwaities ,25.6% are indians,30.0% are bangladesh,12.2% are asian , 12.1% are arabs) 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 167.5/km2 (68th)
433.8/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $137.450 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $38,875[3] (11th)
GIO (onípípè) Ìdíye 2009
 -  Àpapọ̀ iye $114.878 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $32,491[3] (17th)
HDI (2006) 0.912 (high) (29th)
Owóníná Kuwaiti dinar (KWD)
Àkókò ilẹ̀àmùrè AST (UTC+3)
 -  Summer (DST) (not observed) (UTC+3)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .kw
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 965Àwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. Nominal.
  2. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (.PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Kuwait". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01.