Orílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù Sàhráwì
Orile-ede Sahrawi Arabu Olominira Toseluarailu (SADR) (Lárúbáwá: الجمهورية العربية الصحراوية الديمقراطية, Spánì: [República Árabe Saharaui Democrática] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) je orile-ede ti awon die gba to fowogbaya lori gbogo agbegbe Apailaorun Sahara, amusin ile Spein tele. SADR je lilasile latowo Polisario Front ni February 27, 1976. Ijoba SADR lowolowo n joba lori agbegbe bi 20% to fowogbaya fun. O pe awon agbegbe to wa labe ijoba re ni "Agbegbe Ominira" tabi "Aaye Ainidekun." Orile-ede Morocco lo n sejoba awon agbegbe yioku to si pe ibe ni igberiko Apaguusu. Ijoba SADR gba pe awon agbegbe to wa labe ijoba orile-ede Moroko je "Agbegbe Idurolelori (Occupied Territory) " nigbati Moroko gba pe agbegbe kekere to wa labe SADR je "Aaye Idasi (Buffer Zone)."
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù Sàhráwì Sahrawi Arab Democratic Republic الجمهورية العربية الصحراوية الديمقراطية Al-Jumhūrīyya al-`Arabīyya aṣ-Ṣaḥrāwīyya ad-Dīmuqrāṭīyya República Árabe Saharaui Democrática | |
---|---|
Orin ìyìn: Yābaniy Es-Saharā listen | |
Territory claimed by the SADR, viz. Western Sahara. The majority (marked green) is currently administered by Morocco; the remainder (yellow) is named the Free Zone by SADR. | |
Olùìlú | El Aaiún[1] (under Moroccan administration) Bir Lehlou (temporary capital) Tindouf Camps (de facto) Tifariti (proposed new provisional capital)[2][3] |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Arabic, Spanish |
Orúkọ aráàlú | Sahrawi |
Ìjọba | Nominal republic1 |
Brahim Ghali | |
Abdelkader Taleb Oumar | |
Disputed with Morocco | |
November 14, 1975 | |
• SADR proclaimed | February 27, 1976 |
Ìtóbi | |
• Total | [convert: invalid number] (83rd) |
• Omi (%) | negligible |
Alábùgbé | |
• July 2004 estimate | 267 405 (182nd) |
• Ìdìmọ́ra | 1.3/km2 (3.4/sq mi) (228th) |
Ibi àkókò | UTC+0 (UTC) |
Internet TLD | none3 |
1 The SADR government is situated in Tindouf, Algeria. They claim control of the area east of the Moroccan Wall in Western Sahara which they label the Free Zone. Bir Lehlou is within this area.
2 Area of the whole territory of (Western Sahara) claimed by SADR. 3 .eh reserved. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Article 4 of the Sahrawi constitution.
- ↑ "Western Sahara: Polisario Front Continues Destruction of Its Aantipersonnel Landmine Stockpile and Clearance of Cluster Submunitions". Common Dreams. 2008-06-26. http://www.commondreams.org/news2008/0616-10.htm. Retrieved 2009-02-26.
- ↑ Torquemada, Jesus (2008-06-23). "The Referee Rules in Favor of Morocco". http://www.eitb24.com/new/en/B24_102875/world-news/NEWS-ANALYSIS-The-referee-rules-in-favor-of-Morocco/. Retrieved 2009-02-26.