Saint George SC
Saint George Sports Club (Amharic : ቅዱስ ጊዮርጊስ ስፖርት ክለብ, Kidus Giorgis Sport Club), ti inagijẹ rẹ ń jẹ Kidus Giorgis, jẹ ogbontarjgi ẹgbẹ agbabọọlu afẹsẹgba kan ti a da silẹ ni Addis Ababa, Ethiopia. Ẹgbẹ yí ń gba bọọlu ni ipele oke ti bọọlu afẹsẹgba ajumọṣe tí Itiopia (Premier League Ethiopia) . Ti a da ni ọdun 1935, ẹgbẹ naa jẹ akọkọ ni Itiopia ati pe o ti fi idi mulẹ gẹgẹbi aami àtakò ti orilẹ-ede Etiopia tí ó lodi si awọn agbara gbigba tí Fási Ítálì (fascist Italy) .[1]
Full name | Saint George Sports Club | |||
---|---|---|---|---|
Nickname(s) | ፈረሰኞቹ (The Horsemen) አርበኛው (The Patriot) አራዶቹ (The Aradas) ሳንጃው (The Bayonet) | |||
Founded | 1935 (1928 E.C.) | |||
Ground | Addis Ababa Stadium (Capacity: 35,000) | |||
Chairman | Ato Abinet Gebremeskel | |||
Manager | Zerihun Shengeta | |||
League | Ethiopian Premier League | |||
2022-23 | Premier League 1st of 13 | |||
Website | Club home page | |||
|
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Aynshet, Solomon (March 11, 2017). "St. George’s Sport Academy to be inaugurated". waltainfo. http://www.waltainfo.com/index.php/news/detail/28117.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]