Saint Obi
Obinna Nwafor 9 (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún Oṣù Kọkànlá ọdún 1965, tí ó sì kú ní ọjọ́ keje oṣù karùn-ún ọdún 2023) tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Saint Obi, jẹ́ òṣèré ọmọ Nàìjíríà,[1][2] olóòtú fíímù àti olùdarí fíìmù.[3][4][5] Òbí ni a mọ̀ fún àwọn ipa rẹ̀ nínú fíímù Candle Light, State of Emergency, Sakobi, Goodbye Tomorrow, Heart of Gold, Festival of Fire, Executive Crime and Last Party.
Obinna Nwafor | |
---|---|
Fáìlì:Saint-Obi resize.jpg | |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kọkànlá 1965 |
Aláìsí | 7 May 2023 | (ọmọ ọdún 57)
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Jos |
Ìgbà iṣẹ́ | 1996—2023 |
Gbajúmọ̀ fún | Àdàkọ:Bulleted list |
Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ ẹ rẹ̀
àtúnṣeA bí Obi ní ọjọ́ kẹrìndínlógún Oṣù Kọkànlá ọdún1965.[6] Ó ṣe pàtó ìmọ̀ Iṣẹ tiata èyiun Theatre Arts ni University of Jos,[7] ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré-oníṣe ní ọdún 1996 nípasẹ̀ tẹlifisiọnu Peugeot.[8] Ní ọdún 2001, Obi ṣe fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Take Me to Maama, níbití ó ti kópa bí Jerry, papọ̀ pẹ̀lú Ebi Sam, Rachel Oniga, Nse Abel ati Enebeli Elebuwa.
Obi kú ní Oṣù Karùn-ún ọjọ́ keje, ọdún 2023, ní ọmọ ọdún mẹ́tàdínlọ́gọ́ta.[9]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Adebayo, Tireni (24 February 2022). "Actor Saint Obi battles wife in court over custody of their kids". Kemi Filani News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 March 2022.
- ↑ Ukonu, Ivory; THEWILL (25 February 2022). "Veteran Actor Saint Obi In Messy Divorce Drama With Estranged Wife" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 23 November 2022.
- ↑ "Saint Obi’s night of double treats". punchng.com. Archived from the original on 26 August 2014. Retrieved 21 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Saint Obi out with new awards". punchng.com. Archived from the original on 26 August 2014. Retrieved 21 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nollywood Actor Saint Obi Reveals why he stopped acting!". 2shymusic.com. Archived from the original on 9 August 2020. Retrieved 21 August 2014.
- ↑ NF. "Saint Obi: Biography, Career, Movies & More" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 19 May 2019.
- ↑ "Life and Times of Saint Obi". Vanguard News. 2023-05-14. Retrieved 2023-06-02.
- ↑ "Over 500 million watch Nollywood, says Saint Obi". Vanguard. 15 August 2009. http://www.vanguardngr.com/2009/08/over-500-million-watch-nollywood-says-saint-obi/. Retrieved 23 April 2011.
- ↑ Veteran Nolywood actor, Saint Obi dies at 57