Samuel Dedetoku, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Sam Dede látàrí ìṣe rẹ̀(ti wọ́n bí ní 17 Oṣù Kọkànlá ọdún 1965), jẹ́ òṣèré, oníwòsàn, olùdarí éré, olóṣèlú àti olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga láti ìlú Naijiria. Sam Dede jẹ́ olókìkí látàrí àwọn fíìmù tí ó ti ṣe. Ó jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí ìlú Port Harcourt.

Sam Dede
Ọjọ́ìbíSamuel Dedetoku
17 Oṣù Kọkànlá 1965 (1965-11-17) (ọmọ ọdún 59)
Lagos
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Government Comprehensive Secondary School
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Port Harcourt
Iṣẹ́Film director, actor, lecturer, politician, television personality
Ìgbà iṣẹ́1995-present
Olólùfẹ́Tammy Sam-Dede (m. 2001)
AwardsAfrica Movie Academy Award for Best Actor in a Supporting Role
Sam Dede ní ọdún 2021

Ìgbésí ayé

àtúnṣe

A bí Sam Dede ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kọkànlá ọdún 1965 (17 November, 1965) ní ilu Eko ó sì lọ sí ìlú Sapele .

Díẹ̀ nínú àwọn ère tí ó ti jáde

àtúnṣe
  • *Our Jesus Story (2020)
  • The Good Husband (2020) gẹ́gẹ́ bíi Martins
  • The Legend of Inikpi (2020) gẹ́gẹ́ bíi King Attah Ayegba
  • Kamsi (2018) gẹ́gẹ́ bíi Nicholas Katanga
  • In My Country (2017) gẹ́gẹ́ bíi Afam
  • The Lost Number (2012) gẹ́gẹ́ bíi Diwani Wonodi
  • The Mayors (2004)
  • Last Vote (2001)
  • The Last Burial (2000)
  • Issakaba (2000) gẹ́gẹ́ bíi Ebube
  • Igodo (1999)
  • Blood Money (1997) gẹ́gẹ́ bíi Olórí ẹgbẹ́ òkùnkùn
  • Mission to Nowhere (2008) gẹ́gẹ́ bíi Roger
  • Darkest Night (2005)
  • Blood and Oil (2010) gẹ́gẹ́ bíi Gómìnà
  • Bumper to Bumper (2004)
  • Never Die for Love (2004) gẹ́gẹ́ bíi Mark
  • 5 Apostles (2009)
  • Undercover
  • Ijele (1999) as Ijele
  • Ashes to Ashes
  • Gone (2021) as Ani
  • The Black Book (2023) gẹ́gẹ́ bíi Angel
  • Breath of Life (2023) gẹ́gẹ́ bíi Chief Okonkwo
  • Merry Men 3: Nemesis (2023) gẹ́gẹ́ bíi Uduak Francis
  • Here Love Lies (2023) gẹ́gẹ́ bíi Father Abraham
  • The Man Died (2024 film)


Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe