Samuel Frederick Smith (tí a bí ní 19 May 1992) jẹ́ akọrin àti aṣẹ̀dá orin ọmọ orílè-èdè England. Lẹ́yìn tí ó di olókìkí ní oṣù kẹwàá ọdún 2012 nípasẹ̀ ìṣàfihàn rẹ̀ nínú orin àdákọ tí àkọ́lé rè ń jẹ́ " Latch ", èyí tó ṣipò kọkànlá lórí atọ́ka Singles UK. Wọ́n sì padà ṣàfihàn orin "Naughty Boy" tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "La La La" tó ṣịpò kìíní lóṣù karùn-ún, ọdún 2013. Ní oṣù kejìlá ọdún 2013, wọ́n yan Smith fún àmì-ẹ̀yẹ Brit Critics Choice Award, ti ọdún 2014, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ méjèèjì. [6][7]

Sam Smith
Smith performing at the 2015 Lollapalooza
Ọjọ́ìbíSamuel Frederick Smith
19 Oṣù Kàrún 1992 (1992-05-19) (ọmọ ọdún 32)
London, England
Iṣẹ́
  • Singer
  • songwriter
Ìgbà iṣẹ́2008–present
AwardsFull list
Musical career
Irú orin
Instruments
  • Vocals
Labels
Websitesamsmithworld.com

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Kellman, Andy. "Sam Smith Biography & History". AllMusic. Retrieved 12 April 2020. 
  2. Brodesser-Akner, Taffy (1 November 2017). "The Tear-Stained Confessions of Sam Smith". The New York Times. Retrieved 12 April 2020. 
  3. Wahn, Megan (12 November 2017). "Review: Sam Smith drops soulful songs". Red & Black. Retrieved 23 August 2020. 
  4. Murray, Nick (31 March 2014). "Who Is Sam Smith? A Quick Primer on the U.K. Soul Singer". Rolling Stone. Retrieved 12 April 2020. 
  5. "U.K. soul singer Sam Smith comes out". USA Today. 29 May 2014. Retrieved 12 April 2020. 
  6. "Brits announce Critics' Choice 2014 shortlist". BBC. 5 December 2013. Retrieved 19 December 2013. 
  7. "Sound of 2014 Profile: Sam Smith". BBC. Retrieved 10 January 2014.