Ahmed Sani Yerima

Olóṣèlú Naijiria
(Àtúnjúwe láti Sani Yerima)

Ahmed Rufai Sani Yerima jé olósèlú omo orílé-èdè Naijiria. Ó jé Gómìnà Ipinle Zamfara lati 1999 di 2007. Lowolowo o n ni Alagba asofin fun Zamfara West ni Ile-igbimo Asofin Naijiria

Ahmed Rufai Sani
Governor of Zamfara State
In office
29 May 1999 – 29 May 2007
AsíwájúJibril Yakubu
Arọ́pòMahmud Shinkafi
Senator, Zamfara West
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2007
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí22 July 1960
Anka, Zamfara State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress (APC)