Sarah Michael

Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà

Sarah Michael tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìlélógún ọdún 1999 (22 July 1990) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin ọmọ Nàìjíríà. Ó jẹ́ Agbábọ́ọ̀lù-sáwọ̀n.[1]

Sarah Michael
Sarah Michael.jpg
Personal information
OrúkọSarah Michael
Ọjọ́ ìbí22 Oṣù Keje 1990 (1990-07-22) (ọmọ ọdún 34)
Ibi ọjọ́ibíÌbàdàn, Nàìjíríà
Ìga1.72 m
Playing positionAgbábọ́ọ̀lù-sáwọ̀n
Club information
Current clubMallbackens
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Summer Queens
2008–2009Ebony Queens
2009Piteå IF6(1)
2010Djurgården19(7)
2011–2015Örebro86(37)
2018Lidköpings25(5)
2019Kvarnsvedens IK22(5)
2020-Mallbackens18(7)
National team
2008–Ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà5(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 19:15, 29 February 2020 (UTC). † Appearances (Goals).

Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ìkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin tí Nàìjíríà, ó sìn wà lára àwọn ìkọ̀ obìnrin agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí ìdíje bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá Olympics lọ́dún àti ìdíje 2011 World Cup.[2]

Àwọn ìtọ́kasí ìta

àtúnṣe

Àdàkọ:Nigeria Squad 2008 Summer Olympics (Women's Football) Àdàkọ:Nigeria Squad 2011 Women's World Cup


Àdàkọ:Nigeria-women-footy-bio-stub

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 2011 squad Archived 8 October 2011 at the Wayback Machine. in Örebro's website
  2. Statistics in FIFA's website