Saworoide jẹ́ eré àgbéléwò tí Tunde Kelani darí àti tí Mainframe Films àti Television Production ṣe àgbéjáde rẹ̀ ní ọdún 1999.

Àkójọ

àtúnṣe

Saworoide ṣe àfihàn ètò àṣà yorùbá pípẹ́ kan ní ìlú Jogbo níbi tí èèyàn kò lè jẹ oba láìjé  pé èèyàn tó tọ́ lú ìlu saworoide.[1]

Àwọn tó kópa

àtúnṣe
  • Ayantunji Amoo
  • Kunle Bamtefa
  • Kayode Olaiya
  • Yemi Shodimu
  • Kola Oyewo
  • Lere Paimo
  • Bukky Wright
  • Khabirat Kafidipe
  • Kunle Afolayan

Àwọn ìtókasí

àtúnṣe
  1. Eniola, Babatunde (3 January 2014). "THE MYSTERY `SAWOROIDE`". Rough Africa. Retrieved 5 November 2015. 

Kíkà síwájú

àtúnṣe

ìjápọ Ìta

àtúnṣe