Sefi Atta
Sefi Atta (tí a bí ní oṣù kínní ọdun 1964) jẹ́ Olùkọ̀wé ará ìlú Nàìjíríà mọ́ Amẹ́ríkà.[1] Wọ́n ti túfọ̀ àwọn oríṣiríṣi èdè, wọ́n ti ka àwọn ìwé rẹ̀ lórí ẹ̀rọ asọ̀rọ̀ má gbesì bi BBC, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìtàgé tí ó ṣe ni wọ́n ti tún ṣe káàkiri àgbáyé. Àwọn àmì ẹyẹ tí ó ti gbà ni Wole Soyinka Prize for Literature in Africa ti ọdun 2006 àti Noma Award for Publishing in Africati ọdun 2009.[2][3]
Sefi Atta | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Oṣù Kínní 1964 (ọmọ ọdún 60) Ìpínlẹ̀ Èkó , Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè |
|
Ẹ̀kọ́ | |
Iṣẹ́ |
|
Notable work | Everything Good Will Come |
Website | sefiatta.com |
Ìtàn ìgbésí ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Atta ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Orílẹ̀-èdè Nàíjíría, ní oṣù kínní ọdun 1964, sínú ìdílé ọmọ márùn-ún. Baba rẹ̀, Abdul-Aziz Atta ni akọ̀wé Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà títí di ìgbà tí ó fáyé sílè ní ọdun 1972, ìyá rẹ̀, Iyabo Atta ni ó tọ dàgbà.[4]
Ó lọ ilé-ìwé Queen's College ti ìpínlè Èkó, àti Millfield School ní England. Ní ọdun 1985, ó gba àmì-èye B.A. degree ní Birmingham University.
Ó fé Gboyega Ransome-Kuti, Dókítá ìsègùn òyìnbó, àti ọmọ Olikoye Ransome-Kuti, wón sì bí ọmọbìnrin kan, Temi.[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Sefi Atta – Short bio – Q&A (panellist) – Australian Broadcasting Corporation, 27 August 2012. Retrieved 2 September 2012.
- ↑ "Sefi Atta", Myriad Editions.
- ↑ Janine, "New: Acclaimed NOMA Award Winner Sefi Atta’s Latest Novel, A Bit of Difference" Archived 2015-08-23 at the Wayback Machine., Times Books LIVE, 22 August 2014.
- ↑ "Atta, Sefi 1964- | Encyclopedia.com". www.encyclopedia.com. Retrieved 2022-05-25.
- ↑ "Atta, Sefi 1964–", Encyclopedia.com.