Segun Akinola
Segun Akinola
ẹ̀yà | akọ |
---|---|
country of citizenship | Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan |
orúkọ àfúnni | Segun |
orúkọ ìdílé | Akinọlá |
ọjó ìbí | 1993 |
languages spoken, written or signed | gẹ̀ẹ́sì |
iṣẹ́ oòjọ́ rẹ̀ | composer |
kẹ́ẹ̀kọ́ ní | Royal Birmingham Conservatoire, National Film and Television School, Bedford Modern School |
work period (start) | 2012 |
award received | Breakthrough Brits |
official website | http://www.segunakinola.com |
Segun Akinola (tí a bí ní ọdún 1993) jẹ́ aṣẹ̀dá orin Gẹ̀ẹ́sì fún fíìmù lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán àti àwọn àkójọ ìtàn. Ó gba iṣẹ́ lẹ́yìn Murray Gold gẹ́gẹ́ bíi olùdarí àti aṣẹ̀dá orin ti Doctor Who láti "The Woman Who Fell To Earth" ní ọdún 2018 títí wọ "The Power of the Doctor" ní ọdún 2022.[1]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé
àtúnṣeAkinola jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú Britani.[2] Gẹ́gẹ́ bí ọmọdé, ó kọ́ bí wọ́n ṣe ń tẹ dùrù àti bí wọ́n ṣe ń lu ìlù.[3] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Bedford Modern School,[4] àti ní Royal Birmingham Conservatoire,[5] níbi tí ó ti jáde pẹ̀lú first-class ní ọdún 2014.[3] Ó gba oyè ẹ̀kọ́ MA nínú ẹ̀kọ́ Composing for Film and Television, ní National Film and Television School.[3][6]
Àwọn orin rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Àkọ́lé | Ọ̀rọ̀ |
---|---|---|
2012 | Outsiders | Short |
2013 | Frozen Echoes | |
GT4 Challenge of Great Britain Donington Park | Documentary short | |
Godsweeper | Video game | |
2014 | Wings | Short |
1 Way Up: The Story of Peckham BMX | Documentary feature | |
2015 | Shaun the Sheep the Movie Green Light to Opening Night | Documentary series |
Vienna Ugly | Documentary short | |
2016 | The Trip[6] | Short |
White Paint | ||
Paul | ||
A Moving Image[5] | Film | |
The Proposal | Short | |
Dear Mr Shakespeare: Shakespeare Lives[5] | ||
Panorama -The VIP Paedophile Ring: What's the Truth?[6] | Documentary series | |
Black and British: A Forgotten History[5] | ||
2017 | Wild Horses | Short |
Acta Non Verba | Documentary | |
The Human Body: Secrets of Your Life Revealed[5] | TV series | |
Expedition Volcano[5] | Documentary series | |
Custom Love | Short | |
2018 | Wonders of the Moon | Documentary |
2018–2022 | Doctor Who | TV series, Series 11, 12, 13, 2022 specials |
2018 | Itsy | Short |
2021 | Stephen | TV series |
9/11: Inside the President’s War Room | Documentary |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Laford, Andrea (20 July 2022). "Composer Segun Akinola reveals special for BBC centenary is his last Doctor Who job". CultBox. Headline News.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedMartin
- ↑ 3.0 3.1 3.2 "Birmingham graduate is the sound of 'Doctor Who' - Royal Birmingham Conservatoire". Birmingham City University. Retrieved 9 December 2018.
- ↑ "OBMs Crowdfund for new film". Bedford Modern. 15 January 2015. Archived from the original on 12 June 2018. Retrieved 28 January 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 5.0 5.1 5.2 5.3 5.4 5.5 Jeffery, Morgan (26 June 2018). "Doctor Who series 11 composer has been revealed". Digital Spy. http://www.digitalspy.com/tv/doctor-who/news/a860312/doctor-who-series-11-composer-music/. Retrieved 26 June 2018.
- ↑ 6.0 6.1 6.2 "New series of Doctor Who to be scored by composer Segun Akinola". Doctor Who. 26 June 2018. Retrieved 9 December 2018.