Separate (Orin)

Orin àdàkọ ti ọdún 2016 láti ọwó Amanda Black

"Separate" jẹ́ orin láti ọwọ́ olórin orílẹ̀-èdè South Africa ìyẹn Amanda Black, èyí tí ó gbé jáde gẹ́gẹ́ bíi orin àdàkọ rẹ̀ kejì léyìn tí ó ṣàgbéjáde àwò-orin àkọ́kọ́ rẹ̀, ìyẹn Amazulu. Wọ́n fọn ká sí oríṣiríṣi abala rédíò káàkiri ilẹ̀ South Africa ní ọdún 2016. Lẹ́yìn tí wọ́n gbé orin yìí jáde, ó bọ́ sí ipò kìíní lórí Metro FM. Ó bọ́ sí ipò kìíní ní orí àtẹ South African iTunes R&B.Sjava tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olórin Ambitiouz Entertainment ló kọ orin "Separate" sílẹ̀, Christer ló sì ṣiṣẹ́ olùdarí orin náà.

"Separate"
Single by Amanda Black
from the album Amazulu
ReleasedOṣù Kọkànlá 7, 2016 (2016-11-07)
Recorded2016
Genre
LengthÀdàkọ:Duration
LabelAmbitiouz
Songwriter(s)Jabulani Hadebe
Producer(s)
  • Christer
  • Sammy
Amanda Black singles chronology
"Amazulu"
(2016)
"Separate"
(2016)
"Lila"
(2016)

Àhunpọ̀ orin

àtúnṣe

"Separate" jẹ́ orin tó lọ wọ́rọ́wọ́, pẹ̀lú dùrù àti ọ̀pọ̀ ohùn. Sjava ló kọ́kọ́ kọ orin yìí kalẹ̀, tí Saudi (ọ̀kan lára àwọn alábàáṣiṣẹ́pọ̀ rẹ̀) sì dá sí orin náà. Ó jẹ́ orin tó múni lọ́kà gidi gan-an.

Ìgbóríyìn fún

àtúnṣe

Orin náà "Separate" gba àmì-ẹ̀yẹ Best R&B Single ní Metro FM Music Awards ẹlẹ́ẹ̀kẹẹ̀dógún irú ẹ̀.

Ọdún Ayẹyẹ ìgbàmì ẹ̀yẹ Àpèjúwe àmì-ẹ̀yẹ Èsì Ìtọ́ka
2017 Metro FM Music Awards Best R&B Single Gbàá [1]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Reporter, Citizen. "Amanda Black gets her first award and Twitter goes crazy". citizen.co.za. Retrieved 15 September 2017.