Shalewa AshafaYo-Shalewa Ashafa.ogg gbó (tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù keje ọdún 1995) tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ sí ShallyStar jẹ́ òṣèrébìnrin Nollywood tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú eré Ajoche àti The Razz Guy.[1][2]

Shalewa Ashafa
Ọjọ́ìbí12 Oṣù Keje 1995 (1995-07-12) (ọmọ ọdún 29)
Ìpínlẹ̀ Ogun
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Orúkọ mírànShallyStar
Iléẹ̀kọ́ gígaYunifásitì ìpínlẹ̀ Èkó
Iṣẹ́òṣèrébìnrin
Notable workThe Razz Guy

Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Shalewa Ashafa jẹ́ àbíkẹ́yìn àwọn òbí rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun .[2][3] Ó lọ ilé-ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ní Christ the Cornerstone Nursery àti Primary School, GRA Ikeja, Èkó ó sì lọ ilé-ìwé Sẹ́kọ́ndírì rẹ̀ ní Iloko Model College ní ìpínlẹ̀ Osun. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ nínú ìpolongo ọjà ní Yunifásítì ìlú Èkó.[1][3][2]

Àtòjọ àwọn fíìmù tí ó ti ṣe

àtúnṣe

Evol (2017),

There is Something,

The Razz Guy,

Blood Covenant.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "I’m a fantastic actress - Shalewa Ashafa". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-25. Retrieved 2022-08-03. 
  2. 2.0 2.1 2.2 Cyril (2022-02-01). "My talent is my selling point – Omoshalewa". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-03. 
  3. 3.0 3.1 "Getting big roles is sometimes based on who you know — Shalewa Ashafa". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-02. Retrieved 2022-08-03.