Shimon Peres
Shimon Peres (ìrànwọ́·ìkéde), GCMG (Hébérù: שמעון פרס, abiso Szymon Perski; 2 August 1923 - 28 September 2016)[1] ni Aare ikesan lowolowo orile-ede Israel. Peres je served twice as the Alakoso Agba ile Israel kejo lemeji ati gege bi Alakoso Agba Igbadie lekan, be sini o ti je omo awon kabineti 12 ninu ise oloselu to ju odun 66 lo.[2] Peres je didiboyan si Knesset ni November 1959, ayafi fun osu meta ni ibere 2006, o wa nibe titi di 2007, nigba to di Aare.
Shimon Peres שמעון פרס | |
---|---|
President of Israel | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 15 July 2007 | |
Alákóso Àgbà | Ehud Olmert Benjamin Netanyahu |
Asíwájú | Moshe Katsav |
Prime Minister of Israel | |
In office 4 November 1995 – 18 June 1996 Acting until 22 November 1995 | |
Ààrẹ | Ezer Weizman |
Asíwájú | Yitzhak Rabin |
Arọ́pò | Benjamin Netanyahu |
In office 13 September 1984 – 20 October 1986 | |
Ààrẹ | Chaim Herzog |
Asíwájú | Yitzhak Shamir |
Arọ́pò | Yitzhak Shamir |
In office 22 April 1977 – 21 June 1977 Acting | |
Ààrẹ | Ephraim Katzir |
Asíwájú | Yitzhak Rabin |
Arọ́pò | Menachem Begin |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Szymon Perski 2 Oṣù Kẹjọ 1923 Wiszniewo, Poland (now Vishneva, Belarus) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Kadima (2005–present) |
Other political affiliations | Mapai (1959–1965) Rafi (1965–1968) Labor (1968–2005) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Sonya Gelman Peres (1945-2011) |
Àwọn ọmọ | Zvia Yoni Hemi |
Signature |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "President Shimon Peres celebrates 85th birthday". Jerusalem Post. 2008-08-21. Retrieved 2008-08-28.
- ↑ Amiram Barkat. "Presidency rounds off 66-year career". Haaretz. Archived from the original on 2007-09-04. Retrieved 2010-07-24.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Shimon Peres |