Bẹ̀lárùs

(Àtúnjúwe láti Belarus)

Belarus, (pípè /bɛləˈruːs/ (Speaker Icon.svg listen) bel-ə-ROOS; Bẹ̀l. Беларусь, Rọ́síà: Беларусь or Белоруссия, Belorussia see Etymology), lonibise bi Orile-ede Olominira ile Belarus, je orile-ede ayikanule ni Apailaorun Europa,[4] to ni bode bi owo-ago pelu Rosia ni ariwailaorun, Ukrein ni guusu, Poland ni iwoorun, ati Lithuania ati Latvia si ariwaiwoorun. Oluilu re ni Minsk; awon ilu re pataki miran tun ni Brest, Grodno (Hrodna), Gomel (Homiel), Mogilev (Mahilyow) ati Vitebsk (Viciebsk). Idalogorun ogoji 207,600 square kilometres (80,200 sq mi) re lo je igbo aginju,[5] be sini apa okowo re to tobijulo ni ise agbe ati ise elero.

Рэспубліка Беларусь
Республика Беларусь
Republic of Belarus
Àsìá Ẹ́mblẹ́mù Orílẹ̀-èdè
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèДзяржаўны гімн Рэспублікі Беларусь  (Belarusian)
Dziaržaŭny himn Respubliki Biełaruś  (transliteration)
State Anthem of the Republic of Belarus

Ibùdó ilẹ̀  Bẹ̀lárùs  (green) on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Bẹ̀lárùs  (green)

on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Minsk
53°55′N 27°33′E / 53.917°N 27.55°E / 53.917; 27.55
Èdè àlòṣiṣẹ́ Belarusian
Russian[1]
Orúkọ aráàlú Ará Bẹ̀lárùs
Ìjọba Presidential republic
 -  President Alexander Lukashenko
 -  Prime Minister Sergei Sidorsky
Independence from the Soviet Union 
 -  Declared 27 July 1990 
 -  Established 25 August 1991 
 -  Completed 25 December 1991 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 207,600 km2 (85th)
80,155 sq mi 
 -  Omi (%) negligible (2.830 km2)1
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 9,648,533[2] (86th)
 -  1999 census 10,045,200 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 46.7/km2 (142nd)
120.8/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $120.750 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $12,737[3] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2009
 -  Àpapọ̀ iye $48.973 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $5,165[3] 
Gini (2002) 29.7 (low
HDI (2007) 0.826 (high) (68th)
Owóníná Belarusian ruble (BYR)
Àkókò ilẹ̀àmùrè EET (UTC+2)
 -  Summer (DST) EEST (UTC+3)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .by
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 375
1 "FAO's Information System on Water and Agriculture". FAO. Retrieved 2008-04-04. 


ItokasiÀtúnṣe

  1. Àdàkọ:Belarus Constitution
  2. People: Belarus CIAThe World Factbook
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Belarus". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21. 
  4. UN Statistics Division (2010-04-01). "Standard Country and Area Codes Classifications (M49)". United Nations Organization. Retrieved 2010-04-22. 
  5. "Belarus: Window of Opportunity (see Table 15, page 66)" (PDF). United Nations.