Shoki Sebotsane (bíi ni ọjọ́ kẹwàá, oṣù kẹjọ ọdún 1977) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipá Celia Kunutu tí ó kó nínú eré Skeem Saam.[1] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Prudebs Secondary School kí ó tó tesiwaju sì ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Tampere University of Technology. Wọn yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ Golden Horn Award.[2]

Shoki Sebotsane
Ọjọ́ìbíReshoketswe Portia Mmola
10 Oṣù Kẹjọ 1977 (1977-08-10) (ọmọ ọdún 47)
Tzaneen, South Africa
Ẹ̀kọ́Prudens Secondary
Tampere University of Technology
Iṣẹ́
Ìgbà iṣẹ́2000–Present
Olólùfẹ́Sello Sebotsane
Àwọn ọmọOratilwe Kutloano Sebotsane

Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe

àtúnṣe
Àkọ́lé Ipa tí ó kó
Death of a Queen Grace Lerothodi
eKasi: Our Stories Mapula
Mfolozi Street Matshidiso Mofokeng
Muvhango Tumi
My Perfect Family Dawn
Rhythm City Patricia
Skeem Saam Ma Kunutu

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe