Silverbird Galleria
Silverbird Galleria jẹ́ ilé-ìtàjà àti ààyè fún eré-ìdárayá ní Victoria Island, Lagos.[1]
Ìtàn
àtúnṣeWọ́n ṣe ìdásílẹ̀ Silverbird Galleria ní ọdún 2004, láti ọwọ́ ẹgbẹ́ Silverbird,[2] tí í ṣe ilé-iṣẹ́ ìgbéròyìnjáde àti òǹtàjà ilé àti ilẹ̀ tí Ben Murray-Bruce ṣe ìdásílẹ̀ rẹ̀ ní ọdún 1980. Ilé ìwò fíìmù náà, Silverbird Cinema tí ó mú ìyípadà bá ètò sinimá ní Nàìjíríà[3] tí ó sì jẹ́ aṣáájú fún àwọn ìwò ní ilẹ̀ Africa. Sinimá yìí tún ní ẹ̀ka lóríṣiríṣi ní Lagos, Abuja, Port Harcourt, Uyo àti Accra, Ghana.
The Lagos Galleria
àtúnṣeÀwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ Kevin Archer; M. Martin Bosman; M. Mark Amen; Ella Schmidt (2013). Cultures of Globalization: Coherence, Hybridity, Contestation Rethinking Globalizations. Routledge. p. 60. ISBN 9781317996637. https://books.google.com/books?id=Smqfl7gk3wcC&dq=Silverbird+Group+Nigeria&pg=PA214.
- ↑ Leo Zeilig (2009). Class Struggle and Resistance in Africa. Haymarket Books. ISBN 9781931859684. https://books.google.com/books?id=vrjbAgAAQBAJ&dq=Silverbird+Group+Lagos+Nigeria&pg=PA3.
- ↑ Richard Imhoagene (7 February 2015). "Victoria Island – Lagos". Nigerian observer. Archived from the original on 18 May 2015. https://web.archive.org/web/20150518065528/http://www.nigerianobservernews.com/2015/02/07/victoria-island-lagos/. Retrieved 8 April 2015.
External links
àtúnṣe- Silverbird Group Archived 2018-06-18 at the Wayback Machine.
- Silverbird Cinemas