Simón Bolívar

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Spain

Simón José Antonio de la Santísima Trinidad Bolívar y Palacios, to gbajumo bi Simón Bolívar (Pípè: [siˈmon boˈliβar]; July 24, 1783 – December 17, 1830) je ara Venezuela olori ologun ati oloselu. Lapamo pelu José de San Martín, o ko ipa pataki ninu iyorisirere ikija fun ilominira Latin America kuro lowo Ileobaluaye Spein.

Simón Bolívar
Oil painting by Ricardo Acevedo Bernal
Aare ile Venezuela
In office
August 6, 1813 – July 7, 1814
AsíwájúCristóbal Mendoza
In office
February 15, 1819 – December 17, 1819
Arọ́pòJosé Antonio Páez
Aare ile Gran Kolombia
(Colombia, Venezuela, Ecuador, Panama)
In office
December 17, 1819 – May 4, 1830
Vice PresidentFrancisco de Paula Santander
Arọ́pòDomingo Caycedo
Aare ile Bolivia
In office
August 12, 1825 – December 29, 1825
Arọ́pòAntonio José de Sucre
Aare ile Peru
In office
February 17, 1824 – January 28, 1827
AsíwájúJosé Bernardo de Tagle, Marquis of Torre-Tagle
Arọ́pòAndrés de Santa Cruz
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1783-07-24)Oṣù Keje 24, 1783
Caracas, Venezuela
AláìsíDecember 17, 1830(1830-12-17) (ọmọ ọdún 47)
Santa Marta, Colombia
(Àwọn) olólùfẹ́María Teresa Rodríguez del Toro y Alaysa
Signature

Leyin ijabori re lori Oba Spein, Bolívar kopa ninu ifidimule isokan awon orile-ede alominira akoko ni Latin America, to je Gran Kolombia, to si je Aare re lati 1819 de 1830.

Simón Bolívar je mimo ni Latin America bi akoni, ogboju, olujidide ati atuninigbekun. Nigba igbesiaye soki re o lewaju Bolivia, Colombia, Ecuador, Panama, Peru, ati Venezuela lo si ilominira, o si kopa lati se ifidimule fun oro oselu ni Amerika elede Spani. Fun idi eyi won n pe ni "George Washington ti Guusu Amerika".[1][2] [3]

  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2011-01-30. Retrieved 2010-08-07. 
  2. "Ẹda pamosi" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2010-06-18. Retrieved 2010-08-07. 
  3. "Historia y biografía de Simón Bolívar". Historia y biografía de (in Èdè Sípáníìṣì). 2017-10-31. Retrieved 2018-05-13.