Simón Bolívar
Simón José Antonio de la Santísima Trinidad Bolívar y Palacios, to gbajumo bi Simón Bolívar (Pípè: [siˈmon boˈliβar]; July 24, 1783 – December 17, 1830) je ara Venezuela olori ologun ati oloselu. Lapamo pelu José de San Martín, o ko ipa pataki ninu iyorisirere ikija fun ilominira Latin America kuro lowo Ileobaluaye Spein.
Simón Bolívar | |
---|---|
Oil painting by Ricardo Acevedo Bernal | |
Aare ile Venezuela | |
In office August 6, 1813 – July 7, 1814 | |
Asíwájú | Cristóbal Mendoza |
In office February 15, 1819 – December 17, 1819 | |
Arọ́pò | José Antonio Páez |
Aare ile Gran Kolombia (Colombia, Venezuela, Ecuador, Panama) | |
In office December 17, 1819 – May 4, 1830 | |
Vice President | Francisco de Paula Santander |
Arọ́pò | Domingo Caycedo |
Aare ile Bolivia | |
In office August 12, 1825 – December 29, 1825 | |
Arọ́pò | Antonio José de Sucre |
Aare ile Peru | |
In office February 17, 1824 – January 28, 1827 | |
Asíwájú | José Bernardo de Tagle, Marquis of Torre-Tagle |
Arọ́pò | Andrés de Santa Cruz |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Caracas, Venezuela | Oṣù Keje 24, 1783
Aláìsí | December 17, 1830 Santa Marta, Colombia | (ọmọ ọdún 47)
(Àwọn) olólùfẹ́ | María Teresa Rodríguez del Toro y Alaysa |
Signature |
Leyin ijabori re lori Oba Spein, Bolívar kopa ninu ifidimule isokan awon orile-ede alominira akoko ni Latin America, to je Gran Kolombia, to si je Aare re lati 1819 de 1830.
Simón Bolívar je mimo ni Latin America bi akoni, ogboju, olujidide ati atuninigbekun. Nigba igbesiaye soki re o lewaju Bolivia, Colombia, Ecuador, Panama, Peru, ati Venezuela lo si ilominira, o si kopa lati se ifidimule fun oro oselu ni Amerika elede Spani. Fun idi eyi won n pe ni "George Washington ti Guusu Amerika".[1][2] [3]
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2011-01-30. Retrieved 2010-08-07.
- ↑ "Ẹda pamosi" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2010-06-18. Retrieved 2010-08-07.
- ↑ "Historia y biografía de Simón Bolívar". Historia y biografía de (in Èdè Sípáníìṣì). 2017-10-31. Retrieved 2018-05-13.