Ekpa Simon Njoku[2] (tí wọ́n bí lọ́jọ́ 21 oṣù March, ọdún 1985), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Simon Ekpa, jẹ́ òṣèlú àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ-ènìyàn ọmọ orílẹ̀-èdè Finland àti Nigeria tó ń jà fún ìgbòmìnira ìlẹ̀ Biafra láti dá dúró fún ara rẹ̀[3][4] Lọ́dún 2022, nígbà tí ó wà l'órílẹ̀ èdè Finland, ó dá kéde ìgbòmìnira ìjọba ìlẹ̀ Biafra tí ń ṣàtìpó n'ílẹ̀ odi, (BGIE), bẹ́ẹ̀ náà lọ́dún 2023 ó kéde ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Olórí Ààrẹ ìjọba (titled "Prime Minister") tí ń ṣàtìpó n'ílẹ̀ àjèjì.[5][6][lower-alpha 1][10][11]

Simon Ekpa
Ekpa in 2023
Ọjọ́ìbí21 Oṣù Kẹta 1985 (1985-03-21) (ọmọ ọdún 39)
Ohaukwu, Ebonyi State, Nigeria
Ọmọ orílẹ̀-èdèFinnish
Iṣẹ́
  • Politician
  • businessman
Ìgbà iṣẹ́2012–present[1]
Organization
  • Biafra Republic Government in Exile (BRGIE)
  • Biafra Defence Forces (BDF)
  • Biafra Liberation Army (BLA)
Gbajúmọ̀ fúnBiafra restoration
Political partyNational Coalition Party
MovementIndependence of Biafra
Opponent(s)The Nigerian state
AwardsAmbassador for Peace
Signature

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Staff, Daily Post (12 March 2024). "Simon Ekpa: Journey from track athlete to Prime Minister of Biafra Republic Government in Exile". Daily Post Nigeria. 
  2. Ekpa, Simon. "Simon Ekpa". X (formerly Twitter). Retrieved 7 June 2024. I am Ekpa Simon Njoku 
  3. "Nigeria asks Finland to clamp down on Lahti resident and Biafra separatist leader Simon Ekpa". Yle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 17 February 2023. Retrieved 31 December 2023. 
  4. Ariemu, Ogaga (22 June 2024). "Biafra: US Justice Department recognises BRGIE - Ekpa". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 22 June 2024. 
  5. Ariemu, Ogaga (29 May 2024). "Stop using force, threats, engage Finland to mediate – BRGIE to Nigerian govt" (in en-US). Daily Post Nigeria. https://dailypost.ng/2024/05/29/stop-using-force-threats-engage-finland-to-mediate-brgie-to-nigerian-govt/. 
  6. Amin_3 (23 April 2024). "Stay off our lands- Biafra Liberation Army warns Bandits, Terrorists - Peoples Daily Newspaper" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 26 May 2024. 
  7. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named YLE June 2023 Simon Ekpa article
  8. "Simon Ekpa: Nigeria's Ipob faction leader arrested in Finland" (in en-GB). BBC News. 23 February 2023. https://www.bbc.com/news/world-africa-64743942. 
  9. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named YLE February 2023 Simon Ekpa article
  10. Staff, Daily Post (12 March 2024). "Simon Ekpa's journey from track athlete to Prime Minister of Biafra Republic Government in Exile". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 5 May 2024. 
  11. "Biafran Agitator, Simon Ekpa Takes Responsibility For Killing Of Four Nigerian Policemen In Owerri | Sahara Reporters". saharareporters.com. Retrieved 31 July 2024. 


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/> tag was found