William Lawrence Bragg

(Àtúnjúwe láti Sir Lawrence Bragg)

Sir William Lawrence Bragg CH OBE MC FRS[1] (31 March 1890 – 1 July 1971) ni o kere ju ninu awon eni ti o ti gba Nobel Prize titi di odun 2001. Omo Australia ara Britani ni. Omo odun marundinlogbon ni o je nigba ti o gba Nobel Prize ninu fisiksi ni odun 1915.

Sir William Lawrence Bragg
William L. Bragg in 1915
Ìbí(1890-03-31)31 Oṣù Kẹta 1890
North Adelaide, South Australia
Aláìsí1 July 1971(1971-07-01) (ọmọ ọdún 81)
Waldringfield, Ipswich, Suffolk, England
Ọmọ orílẹ̀-èdèBritish
PápáPhysics
Ilé-ẹ̀kọ́University of Manchester
University of Cambridge
Ibi ẹ̀kọ́University of Adelaide
University of Cambridge
Doctoral advisorJ. J. Thomson
W.H. Bragg
Doctoral studentsJohn Crank
Ronald Wilfried Gurney
Ó gbajúmọ̀ fúnX-ray diffraction
Bragg's Law
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physics (1915)
Copley Medal (1966)
Notes
At 25, the youngest person ever to receive a Nobel Prize. He was the son of W.H. Bragg. Note that the PhD did not exist at Cambridge until 1919, and so J. J. Thomson and W.H. Bragg were his equivalent mentors.