Slut Boy Billy
Olórin Ilẹ̀ Ghana
Billy Affou (tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Slut Boy Billy tàbí Slutboy Billy[1]) jẹ́ olórin sùésùé àti òṣèré ti ilẹ̀ Amerika tó tan mọ́ orílẹ̀-èdè Italy àti Ghana.[2][3][4] Ó fìgbà kan ṣiṣẹ́ lábẹ́ ilé-iṣẹ́ Yvonne Nelson tí ó sì kúrò látàri àìlera rẹ̀.[5][6] Ní ọdún 2023, àwọn ènìyàn tó gbọ́ orin àkọ́ṣe rẹ, ìyẹn Mineral Rock ní orí Boomplay jù àádọ́ta ọ̀kẹ́ lọ, bẹ́ẹ̀ sì ni orin náà wà lára ọ̀kan lára orin ọgọ́rùn-ún tó lékè ní South Africa, Egypt, Turkey, Pakistan, Colombia, Bangladesh, àti Brazil.[7][8][9][10]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Sekyi, Lord Kweku (13 August 2018). "American rapper designs clothes for Ghana weather". Ghana Web. Retrieved 19 October 2024.
- ↑ "Slut Boy Billy". Ghana Web. 2024. Retrieved 19 October 2024.
- ↑ Amissah, Francis (24 March 2023). "Slut Boy Billy lays the groundwork for his industry takeover with striking debut EP 'Mineral Rock'". Ghana Web. Retrieved 19 October 2024.
- ↑ Debrah, Ameyaw (2023-03-24). "'Mineral Rock' puts Slut Boy Billy into focus with stellar debut EP - AmeyawDebrah.com" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-10-19.
- ↑ "Slut Boy Billy: a rap prodigy breaking norms, making strides - MyJoyOnline". www.myjoyonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-03-21. Retrieved 2024-10-19.
- ↑ "Meet Slut Boy Billy the Italian native-American raised Ghanaian descent rapper, actor and innovator" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-01-15. Retrieved 2024-10-19.
- ↑ Amissah, Francis (25 May 2023). "Slut Boy Billy zooms past a million streams on Boomplay with 'Mineral Rock EP'". Ghana Web. Retrieved 19 October 2024.
- ↑ Tali, Selorm (2023-05-25). "Slut Boy Billy sets a personal new streaming best with his debut Mineral Rock EP'". Pulse Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-10-19.
- ↑ "Slut Boy Billy's Mineral Rock EP' hits a million streams on Boomplay - MyJoyOnline". www.myjoyonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-05-25. Retrieved 2024-10-19.
- ↑ "Slut Boy Billy's Mineral Rock EP Hits The Million Mark On Boomplay". Peacefmonline.com - Ghana news. Retrieved 2024-10-19.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]