Sofia
Sofia (Bùlgáríà: София, Àdàkọ:IPA-mk) ni oluilu ati ilu titobijulo[2] ni Bulgaria ati ilu titobijulo kejila bi iye awon eniyan ninu Isokan Europe, pelu egbegberun 1.4 eniyan ninu ibe.[3] O budo si apaiwoorun Bulgaria, nibase Oke Vitosha, ibe sini gbongan amojuto, asa okowo ati eko orile-ede na.
Sofia София | |||
---|---|---|---|
| |||
Motto(s): Расте, но не старее (It Grows but Does not Age)[1] | |||
Country | Bulgaria | ||
Province | Sofia-City | ||
Settled by Celts | as Serdica 4th century BC | ||
Government | |||
• Mayor of Sofia | Yordanka Fandakova | ||
Area | |||
• City | Àdàkọ:Infobox settlement/metric/mag | ||
Elevation | 550 m (1,800 ft) | ||
Population (2010.01.15) | |||
• City | ▲1,402,471 | ||
• Density | 1,040/km2 (2,700/sq mi) | ||
• Metro | ▲1,449,277 | ||
Time zone | UTC+2 (EET) | ||
• Summer (DST) | UTC+3 (EEST) | ||
Website | sofia.bg |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Sofia Trough Centuries". Sofia Municipality. Archived from the original on 2009-08-19. Retrieved 2009-10-16.
- ↑ "Таблица на населението по постоянен и настоящ адрес". ГД "Гражданска Регистрация и Административно Обслужване". Retrieved 2008-03-10.
- ↑ "Population table by permanent and present address" (in Bulgarian). Head Direction of Residential Registration and Administrative Service. Retrieved 2010-01-15.