Sola Fosudo
Ṣọlá Fosudo tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kẹta ọdún 1958, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé òun sinimá, ọ̀mọ̀wé,aláríwòye àti adarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2]
Ṣọlá Fosudo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kẹta 1958 |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ |
|
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Ṣọlá ní Ìpínlẹ̀ Èkó, [3], ó kàwé gboyè nínú ìmọ eré oníṣẹ́ láti ilé-ẹ̀kọ Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University àti University of Ìbàdàn, níbi tí ó ti kẹ́kòọ́ gboyè ìkejì nínú ìmọ̀ eré oníṣe.[4] Ó ti kópa nínú eré sinimá oríṣiríṣi tí ó sì tún ti darí òpọ̀lọpọ̀ àwọn eré káàkiri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ati lókè òkun.[5] Òun ni adarí agbà fún ẹ̀ka ètò-ẹ̀kọ́ ti Theatre Art ní ilé-ẹ̀kọ́ ti Lagos State University.[6][7]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
àtúnṣe- True Confession
- Glamour Girls I
- Rituals
- Strange Ordeal
- Ìyàwó Alhaji
- Family on Fire (2011)
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣeÀwọn Ìtàkùn ìjásòde
àtúnṣe- ↑ "Church honour excites Fosudo". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 31 October 2012. Retrieved 20 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nigeria HomePage - Breaking News, Business, Sports, Entertainment and Video News". thenigerianvoice.com. Retrieved 20 February 2015.
- ↑ "I'm not a Nollywood person". The Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2015/02/i-am-not-a-nollywood-person-sola-fosudo/.
- ↑ Olawale Adegbuyi. "MOVIE VETERANS: NIGERIAN FILM ICONS ON PARADE – Part 2". The Movietainment Magazine. Archived from the original on 15 February 2015. Retrieved 20 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2015-02-16. Retrieved 2015-02-16. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nigerian News and Newspapers Online". www.newsng.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2015-02-16. Retrieved 2017-12-22.
- ↑ "Nigeria News Post". nigeriannewspost.com. Archived from the original on 13 October 2020. Retrieved 20 February 2015.