Ilẹ̀ Ọbalúayé Sọ́ngháì
(Àtúnjúwe láti Songhai Empire)
Ile Obaluaye Songhai, bakana bi Ile Obaluaye Songhay, je ile-ijoba Afrika ni iwoorun Afrika. Lati ibere orundun 15th titi de opin orundun 16th, Songhai ni o je ikan ninu awon ile obaluaye Afrika totobijulo ni itan aye. Oruko re wa lati oruko awon eya eniyan to siwaju nibe, eyun awon Songhai. Oluilu re wa ni ilu Gao, nibi ti ile-ijoba Songhai kekere kan ti wa lati orundun 11th. Ibujoko agbara re wa ni koro apa Odo Oya ni orile-ede Niger loni ati Burkina Faso.
|
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |