Sophie Oluwole
Sophie Bosede Oluwole (bíi ni ọjọ́ kejìlá oṣù karùn-ún ọdún 1935) tí orúkọ ìnagi rẹ̀ jẹ́ Iyanifa jẹ́ onímọ̀ ìjìnlè Áfríkà.[1][2] Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má gboyè jáde nínú ìmò ìjìnlè ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[3][4]
Ayé àti iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Sophie ní ọjọ́ kejìlá oṣù karùn-ún ọdún 1935, ó sì jẹ́ ọmọ ìlú Edo. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Lagos níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Philosophy. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ilé ẹ̀kọ́ náà ní ọdún 1972. Ó kú ní ọjọ́ kẹtàlélógún, oṣù kejìlá ọdún 2018.[5]
Àṣàyàn àwọn iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣe- (1992) Witchcraft, Reincarnation and the God-Head (Issues in African Philosophy);
- (1997) Philosophy and Oral Tradition;
- (2014) Socrates and Ọ̀rúnmìlà: Two Patron Saints of Classical Philosophy;[6]
- (2014) African Myths and Legends of Gender (with Akin Sofoluwe).
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Salute to Orunmila as Sophie Oluwole hosts Dutch film-maker". The Punch. December 25, 2017. http://punchng.com/salute-to-orunmila-as-sophie-oluwole-hosts-dutch-film-maker/. Retrieved January 13, 2018.
- ↑ Seada Nourhussen (June 2, 2017). "'Western philosophy has been behind for centuries'". Trouw (in Dutch). Retrieved January 13, 2018.
- ↑ "Philosopher urges Nigerians to embrace indigenous knowledge, languages" (in en-US). The Guardian (Nigeria). Archived from the original on 2019-07-01. https://web.archive.org/web/20190701070051/https://guardian.ng/art/philosopher-urges-nigerians-to-embrace-indigenous-knowledge-languages/.
- ↑ "My mum never believed I could become a professor –Sophie Oluwole".
- ↑ "Buhari, Tinubu, Ofeimun mourn as Sophie Oluwole dies at 83". 24 December 2018. Retrieved 25 December 2018.
- ↑ Ajeluorou, Anote. "Socrates and Orunmila… Putting Premium On Africa’s Indigenous Philosophy". The Guardian (Nigeria). Retrieved 29 April 2018.