Spicy cow feet jẹ́ oúnjẹ aládùn tó wọ́pọ́ ní àwọn ilé ounjẹ , tí a tún mọ̀ sí nkwobi. Irú Oúnjẹ yìí wọ́pọ̀ láàrin àwọn ẹ̀yà Igbo.[1][2] Ó jẹ́ ọbẹ̀ tí a fi òpó ẹ̀sẹ̀ ẹran màlúù sè.[3]

Àwọn èròjà tí a fi n pèsè rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn èròjà tí a ní lò láti fi se ohun ìpanu àwọn ni epo pupa, kaun, èròjà nọ́tmẹẹ̀gì, ewé utazi, ata, alùbọ́sà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ọ̀nà míràn tí a lè potash ni ngu, a lè lo ewé lespinach dípò utazia tí kò bá sí ní tòsí .[4][5][6][7] A sábà máa ń se Nkwobi ní ilé, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó wọ́pọ̀ ní Ilé àwọn oloúnjẹ. Ọbẹ̀ náà wáyé látara ẹsẹ ẹran màlúù tí a ti bọ̀ pẹ̀lú alùbọ́sà àti àwọn oríṣiríṣi èròjà [8][9] Edé Calabash nutmeg àti ata lílọ̀ ní a ma fi kun lẹ́yìn ẹ̀ [10] Ẹ̀sẹ̀ màlúù tí a ti bọ̀ náà ní a ó pòpọ̀ mọ́ òróró, sì rọra ròó kó má báà jóná [11][12]

Ẹ tún wo

àtúnṣe
  • Cow's trotters
  • List of beef dishes
  • List of African dishes
  • Tripe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Staff, Chef's Pencil. "Nkwobi/Spicy Cow Foot Delicacy Recipe". Chef's Pencil (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-06-05. Retrieved 2022-06-05. 
  2. "Nkwobi: Easy Ibo Spicy Cow Foot Delicacy to Die For". 9jafoods (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-12. Retrieved 2022-06-06. 
  3. "Nkwobi: A mouth-watering delicacy from the East!". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-21. Retrieved 2022-06-11. 
  4. says, Fermenting Ugba/Ukpaka-My Diaspora Kitchen (2017-11-17). "Nkwobi: The Nigerian Spicy Cow foot Special.". My Diaspora Kitchen (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-05. 
  5. Dobby (2014-08-09). "How to make Nkwobi". Dobby's Signature (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-06. 
  6. "Nkwobi - Spicy Cow Foot Recipe". Sisi Jemimah (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-10-14. Retrieved 2022-06-06. 
  7. Lete, Nky Lily (2013-02-25). "How to Make Nkwobi : Nigerian Spicy Cow Foot". Nigerian Food TV (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-06. 
  8. "Nkwobi recipe". The Pretend Chef (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-11-29. Retrieved 2022-06-06. 
  9. Travel, Ou; Tour (2020-12-30). "How to make Nkwobi". Ou Travel and Tour (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-11. 
  10. "Nkwobi: Spicy Cow Foot". All Nigerian Recipes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-05. 
  11. "Nkwobi | How To Make Nigerian Desserts". All Nigerian Foods (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-05. 
  12. RITA (2020-09-19). "Food tips: How to make your Nkwobi spicy, yummy!". Vanguard Allure (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-11.