Stella Chineyelu Okoli (bíi ní ọdún 1944)[1] jẹ́ onísègùn àti oníṣòwò[2] ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ní olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ Emzor Pharmaceutical.[3]

Stella Chinyelu Okoli
OON, MON
Ọjọ́ìbí1944 (ọmọ ọdún 79–80)
Kano State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́
Ìgbà iṣẹ́1976–present

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ àtúnṣe

Wọ́n bí Stella sí ìlú Kano sí ìdílé Felix Ebelechukwu àti Margaret Modebelu tí wọ́n sì jẹ́ ọmọ ìran NnewiÌpínlẹ̀ Anámbra.[4] Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ni All Saint Primary School ní ọdún 1954 ní ìlú Onitsha kí ó tó wá lọ sí Ogidi Girls Secondary School. Ní ọdún 1969, Stella gboyè jáde nínú ìmò Pharmacy [[ láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Bradford.[5]

Iṣẹ́ àtúnṣe

Kí o tó dá ilé iṣẹ́ Emzor kalẹ̀, ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ilé ìwòsàn bíi Middlesex Hospital, Boots the Chemists Limited àti Pharma-Deko.[6] Ní oṣù kìíní ọdún 1977, ó dá ilé iṣẹ́ Emzor Pharmaceutical kalẹ̀, ó sì pèé ní Emzor Chemist's Limited.[7] [8] Lẹ́yìn ikú ọmọ rẹ̀ Chike Okoli ní ọdún 2005, ó bẹ̀rẹ̀ ẹgbẹ́ Chike Okoli Foundation ni ọdún 2006, tí ẹgbẹ́ náà sì má ń dojú ìjà kọ ìṣẹ́ àti àrùn.[9][10]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Stella Okoli @70". The Nation Newspaper. 6 August 2014. http://www.thenationonlineng.net/stella-okoli-70/. Retrieved 3 February 2016. 
  2. "Stella Okoli in low 70th birthday celebration". The Nation Newspaper. 9 August 2014. http://www.thenationonlineng.net/stella-okoli-in-low-70th-birthday-celebration/. Retrieved 3 February 2016. 
  3. Inyang, Ifreke (3 February 2012). "Women of distinction! Sefi Atta, Toyosi Akerele, Diezani Alison-Madueke, Florence It-Giwa & others to be honoured at the 17th ThisDay Annual Awards – See The Full List". YNaija. http://www.ynaija.com/men-and-women-of-excellence-full-list-of-nominees-for-the17th-thisday-annual-awards/. Retrieved 3 February 2016. 
  4. "Stella Okoli Shocks Family and Friends". ThisDay Newspaper. 24 August 2014. Archived from the original on 24 February 2016. https://web.archive.org/web/20160224010117/http://www.thisdaylive.com/articles/stella-okoli-shocks-family-and-friends/187227. Retrieved 3 February 2016. 
  5. "Profile of Dr. Stella Okoli". Emerald Energy Resources Limited. Archived from the original on 16 April 2019. Retrieved 3 February 2016. 
  6. "Meet Nigeria’s Most Influential Women". The Street Journal. 30 September 2011. Retrieved 3 February 2016. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  7. Osunnuyi, Adejuwon (30 November 2015). "Nigeria’s ‘lady of drugs’". National Mirror Newspaper. Archived from the original on 5 December 2015. https://web.archive.org/web/20151205110424/http://nationalmirroronline.net/new/nigerias-lady-of-drugs/. Retrieved 3 February 2016. 
  8. "‘I strive to make people happy’". The Nation Newspaper. 12 October 2014. http://www.thenationonlineng.net/i-strive-to-make-people-happy/. Retrieved 3 February 2016. 
  9. "To Make Or Not To Make: Stella Okoli, Emzor Pharmaceuticals". Ventures Africa. Retrieved 3 February 2016. 
  10. Ayobami, John (2 June 2012). "Why we fight poverty, heart diseases – Stella Okoli, MD, Emzor". Vanguard Newspaper. http://www.vanguardngr.com/2012/06/why-we-fight-poverty-heart-diseases-stella-okoli-md-emzor/. Retrieved 3 February 2016.