Stephanie Ndlovu (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1991) jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Scandal àti Shuga. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Johannesburg.[2] Ó jẹ́ ìkan láàrin àwọn atọkun ètò ọmọdé tí àkòrí rẹ jẹ Craz-e.[3][4] Ó ṣe atọkun ètò Bonisanani. Ó kó ipa Ingrid nínú eré Scandal ni ọdún 2015.[5] Ó fẹ́ Hungani Ndlovu ni oṣù kejì ọdún 2019.[6]

Stephanie Sandows
Stephanie ní ọdún 2019[1]
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kẹ̀wá 1991 (1991-10-29) (ọmọ ọdún 32)
Orílẹ̀-èdèSouth African
Ẹ̀kọ́University of Johannesburg
Iṣẹ́
Olólùfẹ́
Hungani Ndlovu (m. 2019)

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named special
  2. Mmakou, Boitumelo (2016-04-26). "5 mins with Stephanie Sandows". Bona Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-10-24. Retrieved 2020-02-08. 
  3. "Isidingo introduces new character, Stephanie Sandows as Olivia Sibeko" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-10-20. Retrieved 2020-02-08. 
  4. Mvelashe, Phakamani (2019-08-22). "Thuli Phongolo on how it felt to be in high school while working on TV". Channel (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-08. 
  5. Mrasi, Athabile (2017-12-07). "Actor Romeo on leaving an abusive relationship". Channel (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-09. 
  6. "Stephanie Sandows says married life has been both 'challenging' and 'rewarding' - here's why". Channel (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-22. Retrieved 2020-05-21.