Steve Agee
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Steven Douglas Agee ( /ˈeɪˌdʒiː/; tí wọ́n bí ní February 26, 1969) jẹ́ apanilẹ́rìn-ín ti Orílẹ̀ èdè America, òǹkọ̀wé àti olórin. Ó tún máa ń tẹ dùrù pẹ̀lú ẹgbẹ́ olórin lóríṣiríṣi, ní ọdún 1990,[1] ó sì ti fìgbà kan ṣẹrẹ́ pọ̀, pẹ̀lú Brendon Small.[2][3]
Steve Agee | |
---|---|
Agee at San Diego Comic-Con International in 2016 | |
Ọjọ́ìbí | Steven Douglas Agee 26 Oṣù Kejì 1969 Riverside, California, U.S. |
Iṣẹ́ | Comedian, actor, writer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2000–present |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Interview with Comedian Steve Agee | PSYCHIC GLOSS MAGAZINE". Archived from the original on 2021-01-21. Retrieved 2023-08-21.
- ↑ "Dethklok on Facebook". Facebook. Archived from the original on 2022-04-30.Àdàkọ:CbignoreÀdàkọ:User-generated source
- ↑ "Scab, by Steve Agee".