Stevie Wonder
(Àtúnjúwe láti Stevland Hardaway Judkins)
Stevland Hardaway Judkins (ojoibi May 13, 1950), o yi oruko re si Stevland Hardaway Morris,[1] eni to gbajumo pelu oruko itage re Stevie Wonder, je akorin, alu ilu orin, olootu awo orin ati alakitiyan ara Amerika.[2] O fo loju laipe ti a bi,[3] Wonder towobowe pelu ile-ise Tamla to je ti Motown Records nigba to je omo odun mokanla,[2] o si untesiwaju lati gbe awo orin re jade nibe titi doni.
Stevie Wonder | |
---|---|
Stevie Wonder at a conference in Salvador, Brazil in July 2006 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Stevland Hardaway Judkins |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Stevland Hardaway Morris, Little Stevie Wonder, Eivets Rednow, El Toro Negro |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Detroit, Michigan, United States |
Irú orin | R&B, pop, soul, funk |
Occupation(s) | Singer-songwriter, multi-instrumentalist, record producer, activist |
Instruments | Vocals, synthesizer, piano, harmonica, drums, bass guitar, congas, bongos, clavinet, melodica, keytar |
Years active | 1961–present |
Labels | Tamla, Motown Records |
Website | http://www.steviewonder.net |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Love, Dennis & Brown, Stacy Blind Faith: The Miraculous Journey of Lula Hardaway, Stevie Wonder's Mother. Simon & Schuster, 2007 ISBN 1-4165-7785-8, 9781416577850 Stevie Wonder's mother's authorized biography states that his surname was legally changed to Morris when he signed with Motown in 1961.
- ↑ 2.0 2.1 Perone, James E. (2006). The Sound of Stevie Wonder: His Words and Music. Westport, CT: Greenwood Publishing. ISBN 0-275-98723-X. Pg. xi-xii
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedincubator