Subrahmanyan Chandrasekhar
Subrahmanyan Chandrasekhar, FRS (Tàmil: சுப்பிரமணியன் சந்திரசேகர்), English: /ˌtʃʌndrəˈʃeɪkɑr/)[2] (October 19, 1910 – August 21, 1995)[3] je onimo fisiksi-irawo omo India Amerika. O je elebun Nobel ninu fisiksi pelu William Alfred Fowler fun ise won lori opo elero ati iyojade awon irawo.[4] O je abatan Elebun Nobel omo India Sir C. V. Raman.
Subrahmanyan Chandrasekhar | |
---|---|
Subrahmanyan Chandrasekhar | |
Ìbí | Lahore, Punjab, British India | Oṣù Kẹ̀wá 19, 1910
Aláìsí | August 21, 1995 Chicago, Illinois, United States | (ọmọ ọdún 84)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | British India (1910–1947) India (1947–1953) United States (1953–1995) |
Pápá | Astrophysics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Chicago University of Cambridge |
Ibi ẹ̀kọ́ | Trinity College, Cambridge Presidency College, Madras |
Doctoral advisor | R.H. Fowler |
Doctoral students | Donald Edward Osterbrock, Roland Winston |
Ó gbajúmọ̀ fún | Chandrasekhar limit |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize, Physics (1983) Copley Medal (1984) National Medal of Science (1966) Padma Vibhushan (1968) |
Religious stance | Hindu atheist[1] |
Chandrasekhar sise ni eka-eko ni Yunifasiti ilu Chicago lati 1937 titi di igba to ku ni 1995 nigba to je omo odun 84. O di araalu orile-ede Amerika ni 1953.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Chandrasekhar: The Man Behind the Legend - Chandra Remembered. By Kameshwar C. Wali - 1997; London: Imperial College Press. ISBN 1-86094-038-2
- ↑ Àdàkọ:Indian name
- ↑ Bio-Chandrasekhar
- ↑ Vishveshwara, S. (25 April 2000). "Leaves from an unwritten diary: S. Chandrasekhar, Reminiscences and Reflections" (.PDF). Current Science 78 (8): 1025–1033. http://www.ias.ac.in/currsci/apr252000/generalia.pdf. Retrieved 2008-02-27.