Suleiman Braimoh

Agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Suleiman Okhaifoede Braimoh Jr. (tí a bí ní October 19, 1989) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlu America. Ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsápẹ̀rẹ̀, tó gbá bọ́ọ̀lù fún Maccabi Tel Aviv, èyí tí í ṣe ti Israeli Basketball Premier League àti Euroleague. Ó tún gbábọ́ọllù fún ilé-ìwé gíga ti Rice University,[1][2] kí ó tó bẹ̀rẹ̀ sím máa gbá bọ́ọ̀lù fún NBA Development League,[3] ní Qatar, Japan, New Zealand, Mexico, Germany, Russia, France, Israel, àti Turkey.

Suleiman Braimoh
Braimoh with the Gießen 46ers in April 2016
Free agent
Power forward / center
Personal information
Born19 Oṣù Kẹ̀wá 1989 (1989-10-19) (ọmọ ọdún 35)
Benin City, Edo, Nigeria
NationalityNigerian / American
Listed height6 ft 8 in (2.03 m)
Listed weight230 lb (104 kg)
Career information
High schoolUnited Nations International School
(New York City, New York)
Lawrenceville School
(Lawrenceville, New Jersey)
CollegeRice (2007–2011)
NBA draft2011 / Undrafted
Pro playing career2011–present
Career history
2011–2012Rio Grande Valley Vipers
2012Al-Gharafa
2013Al Rayyan
2013–2014Niigata Albirex
2014Shinshu Brave Warriors
2014Taranaki Mountainairs
2014–2015Huracanes de Tampico
2015Hawke's Bay Hawks
2015–2016Gießen 46ers
2016–2017Enisey
2017Nanterre 92
2017–2018Enisey
2018–2019Hapoel Eilat
2019–2021Hapoel Jerusalem
2021San Pablo Burgos
2021–2022Hapoel Jerusalem
2022–2023Tofaş
2023Maccabi Tel Aviv
Career highlights and awards

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named bio
  2. "Suleiman Braimoh Stats". Sports-Reference.com. Retrieved April 18, 2014. 
  3. "Mountain Airs get 'big man'". Stuff.co.nz. October 6, 2012. Retrieved April 18, 2014.