Ìpínlẹ̀ Ẹdó
(Àtúnjúwe láti Edo State)
Ìpínlẹ̀ Edo State nickname: Heart Beat of Nigeria | ||
Location | ||
---|---|---|
![]() | ||
Statistics | ||
Governor (List) |
Adams Oshiomhole (AC) | |
Date Created | 27 August 1991 | |
Capital | Benin City | |
Area | 17,802 km² Ranked 22nd | |
Population 1991 Census 2005 estimate |
Ranked 27th 2,159,848 3,497,502 | |
ISO 3166-2 | NG-ED |
Ìpínlẹ̀ Ẹdó jẹ́ ìkan nínú àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó sàgbè pẹ̀lú àríwá àti ìwọ̀ oòrùn ìpínlẹ̀ Kogi, àgbè pẹ̀lú gúúsù ìpínlẹ̀ Delta àti ìlà-oòrùn ìpínlẹ̀ Ondo.
Àwọn ìjọba ìbílẹ̀ lábẹ́ rẹ̀Àtúnṣe
Àwọn ìjọba ìbị́lẹ̀ méjìdínlógun ló wà lábẹ́ ìpínlẹ̀ Edo.
- Akoko-Edo
- Egor
- Esan Central
- Esan North-East
- Esan South-East
- Esan West
- Etsako Central
- Etsako East
- Etsako West
- Igueben
- Ikpoba-Okha
- Oredo
- Orhionmwon
- Ovia North-East
- Ovia South-West
- Owan East
- Owan West
- Uhunmwonde
Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |