Sunday dare
Oníwé-Ìròyín
Sunday Dáre ni a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n, oṣù Kárùún ọdún 1966 (29-5-1966) jẹ́ ògbóntagì oníwèé-ìròyìn ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó ti ṣiṣẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn tí ṣiṣẹ́ ní onírúurú ilé-iṣẹ́ ìgbóhùn sáfẹ́fẹ́ rédíò àti ilé-iṣẹ́ atèwé-ìròyìn, ó sín ní ìmọ̀ tó dáńgájíá fún odidi ọdún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n gbáko nínú iṣẹ́ yìí misanna-agba ti Nigerian Communications Commission (NCC), Aare ( President of the Federal Republic of Nigeria Muhammadu Buhari ni o yan-an si ipo naa ni Osu ikejo odun 2016.[1]
Lowolowo bayii, o je Minisita fun eto nipa odo ati ere-idaraya ti orile-ede Naijiria. Aare Buhari yan-an si ipo minisita ni ojo kokanlegun, Osu keejo, odun 2019. O je omobibi ipinle Oyo.[2]
Awon itokasi
àtúnṣe- ↑ Okogba, Emmanuel; Okogba, Emmanuel (August 21, 2019). "Sunday Dare: Meet new Minister of Sports". Vanguard News. Retrieved September 16, 2019.
- ↑ Oke, Jeremiah (July 23, 2019). "Buhari nominates Sunday Dare as minister – Daily Trust". Daily Trust. Archived from the original on July 27, 2019. Retrieved September 16, 2019.