Sunkanmi Omobolanle jẹ́ òṣèrékùnrin ilẹ̀ Nàìjíríà, àti olùdarí fíìmù.[1][2][3]

Sunkanmi Omobolanle
Ọjọ́ìbí1 March 1981
Oyo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́B.sc Business Administration, Olabisi Onabanjo University
Iléẹ̀kọ́ gígaOlabisi Onabanjo University
Iṣẹ́actor
Notable workKakanjo
Olólùfẹ́Abimbola Bakare
Parent(s)Sunday Omobolanle (father)

Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ tó yàn láàyò àtúnṣe

Ọjọ́ kìíní oṣụ̀ kẹta ọdún 1981 ni wọ́n bí i. Ìlú Ilora ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tó wà ní apá Ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà ni ó ti wá.[4] Òun ni ọmọ gbajúgbajà òṣèrékùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Sunday Omobolanle, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí "Baba Luwee".[5] Ilé-ìwé Nigerian Military School ni ó ti kàwé kí ó tó lọ sí Yunifásítì Olabisi Onabanjo, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè bachelor's degree nínú ìmọ̀ Business administration.[6] Ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Abimbola Bakare, ní ọdún 2011.[7] Ó sì ti ṣe àfihàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ náà ni ó ti dárí ọ̀pọ̀ fíìmù.[8]

Àtòjọ àọn fíìmu rẹ̀ àtúnṣe

  • Olaide Irawo (2007)
  • Gongo Aso (2008)
  • Kakanfo (2020)

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "My husband chats on the phone at ungodly hours— Sunkanmi Omobolanle's wife". Archived from the original on 2014-06-22. Retrieved 2015-02-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Sunkanmi Omobolanle, Chika Agatha crash out Sexiest in Nollywood - Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 2013-08-17. http://www.vanguardngr.com/2013/08/sunkanmi-omobolanle-chika-agatha-crash-out-sexiest-in-nollywood/. 
  3. Adebayo, Tireni (2020-08-21). "Sunkanmi Omobolanle's wife clears the air on baby news". Kemi Filani News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-14. 
  4. Empty citation (help) 
  5. "Actor Sunkanmi Omobolanle Set to Wed". 
  6. Empty citation (help) 
  7. "TheNET.ng - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games". Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-01-03. 
  8. Empty citation (help)