Sunday Ọmọbọ́láńlé tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Papi Luwe (ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1954) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré aláwàdà, olóòtú, oǹkọ̀tàn àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1][2]. Ìyàwó rẹ̀ ni gbajúgbajà òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò, Peju Ogunmola, bẹ́ẹ̀ náà ọmọkùnrin rẹ̀, Súnkànmí Ọmọbọ́láńlé jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré tíátà.

Sunday Omobolanle
Ọjọ́ìbí(1954-01-10)10 Oṣù Kínní 1954
Oyo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànPapi Luwe
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • comic actor
  • filmmaker
  • producer
  • director
  • witter
Olólùfẹ́Peju Ogunmola
Àwọn olùbátanSunkanmi Omobolanle (son)
AwardsMON

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe