Supa Ngwao Museum
Supa Ngwao Museum jẹ́ musíọ́mù kan tí ó wà ní ìlú Francistown ní orílẹ̀ èdè Botswana.[1] Àwọn ohun tí ó wà níbẹ̀ àwọn ǹkan nípa ìtàn, àṣà, ìṣe àti Iṣẹ́ owó àwọn tí ó wà tàbí tí ó ti gbé ní apá àríwá ìwọ̀ oòrùn Botswana ní ayé àtijọ́.[2] Wọ́n sẹ̀dá musíọ́mù náà ní ọdún 1986 láti jẹ́ ilé fún àwọn ohun tó jọ mọ́ ìtàn ìlú Francistown àti àwọn ibi miran ní apá àríwá. Supa Ngwao museum wà láti ṣe ìgbé lárugẹ ìtàn àti àṣà àwọn ènìyàn Kalanga.
Supa Ngwao Museum | |
---|---|
Supa Ngwao Museum ní Francistown, Botswana | |
Building | |
Location | Francistown , Botswana |
Coordinates | 21°10′25″S 27°30′45″E / 21.17361°S 27.51250°E |
Ìtàn
àtúnṣeWọ́n kọ́kọ́ Supa Ngwao museum kalẹ̀ láti sọ nípa ìtàn, àṣà àti Iṣẹ́ owó àwọn ènìyàn Kalanga àti àwọn tí ó ń gbé ní àríwá Botswana.
Àwọn Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "About supa ngwao". Francistown Museum. Archived from the original on 30 November 2020. Retrieved 1 September 2017.
- ↑ https://museum-francistown.org/