Susovan Sonu Roy

Indian osere ati onijo
(Àtúnjúwe láti Susovan. Sonu Roy)
Susovan Sonu Roy
ọmọnìyàn
ẹ̀yàakọ Àtúnṣe
country of citizenshipÍndíà Àtúnṣe
orúkọ ìdíléRoy Àtúnṣe
ọjó ìbí19 Oṣù Agẹmọ 1994 Àtúnṣe
ìlú ìbíHowrah Àtúnṣe
native languageÈdè Bẹ̀ngálì Àtúnṣe
languages spoken, written or signedÈdè Bẹ̀ngálì Àtúnṣe
iṣẹ́ oòjọ́ rẹ̀òṣèré, dancer, òṣeré fíímù, àwòṣe Àtúnṣe
kẹ́ẹ̀kọ́ níDum Dum Motijheel Rabindra Mahavidyalaya Àtúnṣe
work period (start)2019 Àtúnṣe
eye colorblackish-brown Àtúnṣe
hair colorIrun dúdú Àtúnṣe

Susovan Sonu Roy tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkàndínlógún oṣù keje ọdún 1994 jẹ́ ọ̀ṣèré àti oníjó ìgbàlódé ilẹ̀-òkèrè ọmọ India. Àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́n nípa ipa tó kó nínú ètò orí tẹlifíṣàn bí i Anandamoyee Maa lọ́dún (2019) fún pẹpẹ ètò Aakash Aath channel, Mohor (2019), Korapakhi (2020), Titli (2020) fún pẹpẹ tẹlifíṣàn Star Jalsha, àti àwọn ètò mìíràn lórí pẹpẹ Zee Bangla. Kí ó tó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣ'eré, ijó ni ó kọ́kọ́ máa ń jó.[1]

Susovan Sonu Rou
SSR_in_2022_(1)
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Keje 1994 (1994-07-19) (ọmọ ọdún 30)
Howrah
Orílẹ̀-èdèImdia
Iṣẹ́Òṣèré

Iṣẹ́

àtúnṣe

Ìlú Howrah ni wọ́n bí Susovan sí l'órílẹ̀-èdè Indian ṣùgbọ́n ní Kolkata ló gbé dàgbà. Ó kàwé ní Kolkata ní ilé-ẹ̀kọ́ Dum Dum Mothijheel Rabindra Mahavidyalaya lọ́dún 2016.[1][2]

Ọmọ ọdún márùn-ún ló wà tí bàbá rẹ̀ fi kú nínú ìjàm̀bá ọkọ̀. Lásìkò yìí ni wàhálà rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ láyé, òun àti ìyá rẹ̀ dojú kọ ọpọ̀lọ̀pọ̀ ìṣòro. Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn fẹ́ràn Susovan, nítorí tirẹ̀, wọ́n féràn màmá rẹ̀ bákan náà, ó sì nífẹ̀ẹ́ ni èyí púpọ̀.[1][3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 "Susovan Sonu Roy - Biography". IMDb. Retrieved 2024-05-03.
  2. "Bengali Actor Susovan Sonu Roy started his career as a dancer". Kashmir Age. 2022-01-25. Retrieved 2024-05-03.
  3. "Roy starts career as dancer, becomes popular face of Bengali TV series". Meghalaya Monitor. Retrieved 2024-05-03.