Tẹ́tẹ́ ní Nàìjíríà
Tẹ́tẹ́ ní Nàìjíríà kò ní ìmójútó tó dára. Bótilẹ̀ jẹ́ pé òfin wà nípa tẹ́tẹ́, ọ̀pọ̀ àwọn ilé kàlòkàlò (kàsínò) tó wà ní Nàìjíríà kò ní ìwé-àṣe látọwọ́ ìjọba. The Federal Palace Hotel ní ìlú Èkó ni kàsínò tó tóbi jùlọ ní Nàìjíríà wà.