Taaooma
Maryam Apaokagi, tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Taaooma, jẹ́ apanilẹ́rìn-ín ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó tún jẹ́ ayàwòrán[1] Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, òun ni olùdarí àti olùdásílẹ̀ Chop Tao,[2] èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ oúnjẹ, ó sì ń darí ilé-iṣẹ́ Greenade [2] Ó di gbajúgbajà látàrí àwo eré apanilẹ́rì-ín rẹ̀ lórí ẹ̀rọ ayárabíàṣá.[3][4]
Taaooma | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Maryam Apaokagi |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Kwara State University |
Iṣẹ́ | Comedian |
Olólùfẹ́ | Abula (m. 2021) |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀.
àtúnṣeA bí Maryam Apaokagi ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì, ọdún 1999 sí ìlú rẹ̀ ní Ilorin, Ìpínlẹ̀ Kwara, àmọ́ ó lo ìgbà èwe rẹ̀ ní Namibia. Ó kékọ̀ọ́ nípa Tourism and Travel Service Management ní Kwara State University.[5][6][7] Ní ọdún 2022, ó sọ fún ìwé-ìròyin The Punch pé, “mo fẹ́ di dọ́kítà, mo sì tún yí i padà sí agbẹjọ́rò. Àmọ́ ẹ̀kọ́ tourism ni wọ́n fún mi láti lọ kọ́ ní ilé-ìwé”.[8]
Ìgbésí ayé rè.
àtúnṣeNí oṣù kẹwàá, ọdún 2020, wọ́n fi Apaokagi fún ọkọ àfẹ́sọ́nà rẹ̀, tí í ṣeAbdulaziz Oladimeji (tí a tún mọ̀ sí. Abula) ní Namibia,[9] wọ́n sì ṣe ìgbeyàwó ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kìíní, ọdún 2021.[10][11]
Àtòjọ àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeYear | Award | Category | Result | Ref. |
---|---|---|---|---|
2019 | The Gage Awards | Best Online Comedian Of The Year | Gbàá | [12] |
2020 | Nigeria's 25 under 25 awards | Social Entrepreneur | Gbàá | [13] |
The Future Awards Africa | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [14] | ||
Maya Awards (Africa) | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [15] | ||
City People Music Awards | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |||
The Guardian | 100 Most Inspiring Women in Nigeria | Àdàkọ:Shortlisted | [16] | |
2021 | Net Honours | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [17] | |
JCI TOYP Award | Cultural Achievement | Gbàá | [18] | |
2022 | Africa Magic Viewers' Choice Awards | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [19] | |
The Future Awards Africa | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [20] | ||
Net Honours | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [21] |
Tún wo
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "How video editing made me Taaooma, the comedienne – Maryam Apaokagi". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-07-11.
- ↑ 2.0 2.1 "Maryam Apaokagi (@taaooma)". Culture Intelligence from RED. Archived from the original on 5 July 2022. Retrieved 5 July 2022.
- ↑ "How two Nigerian women are breaking into comedy's boys club". Christian Science Monitor. 10 August 2020. Retrieved 8 October 2020.
- ↑ "Who is Taaooma? Unmasking Instagram's unlikely most popular comedian [Pulse Interview]". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-18. Retrieved 2021-03-01.
- ↑ "Comedian Taaooma hits 1m on Instagram, watch how she marks it". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-16. Retrieved 2021-03-01.
- ↑ "Taaooma talks about growing up in Namibia, relationship, popularity and how she switches her roles" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-01-21. Retrieved 2021-03-01.
- ↑ ""My momsy no dey beat me" - Taaooma". BBC News Pidgin. 2020-04-03. Retrieved 2021-03-01.
- ↑ Edeme, Victoria (12 May 2022). "My mum inspires some of my skits, says Taaooma". Punch Newspapers. Retrieved 5 July 2022.
- ↑ "Video: Taaooma, Abula share their engagement story". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-30. Retrieved 2021-03-01.
- ↑ "PHOTOS: Taaooma marks first wedding anniversary". TheCable Lifestyle. 24 January 2022. Retrieved 27 March 2022.
- ↑ Ukonu, Ivory; THEWILL (2022-02-06). "2021 Was A Great Year For Me – Maryam Apaokagi-Greene" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-21.
- ↑ "WINNERS FOR THE GAGE AWARDS 2020 | GAGE AWARDS". Gage Awards. Archived from the original on 27 March 2020. Retrieved 8 October 2020.
- ↑ Udeh, Onyinye (28 August 2020). "Kiki Osinbajo, Taaooma, Kumi Juba, Captain E, Sydney Talker Others nominated for Nigeria's 25 under 25 Awards. » YNaija". YNaija. Retrieved 8 October 2020.
- ↑ "The Future Awards Africa: Class of 2020". November 8, 2020. Archived from the original on October 24, 2021. Retrieved January 20, 2023.
- ↑ "Mayorkun, Taaooma, Lolade Abuta tops 2020 MAYA AWARDS AFRICA Nominees' List". September 28, 2020. Archived from the original on December 2, 2022. Retrieved January 20, 2023.
- ↑ "Leading ladies Africa – 100 Most inspiring women in Nigeria 2020". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-14. Archived from the original on 2023-06-06. Retrieved 2021-03-01.
- ↑ "Net Honours - The Class of 2021". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-07.
- ↑ Olowoporoku, Muhamin. "Taaooma, Asisat Oshoala, others to receive JCI TOYP award". P.M. News. Retrieved 5 July 2022.
- ↑ "2022 Africa Magic Awards Nominees don land- See who dey list". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-60818021.
- ↑ "See who win for The Future Awards 2022". BBC News Pidgin. Retrieved 27 March 2022.
- ↑ Bakare, Simbiat (2 July 2022). "NET Honours 2022: Ikorodu Bois Beats Mr Macaroni, Sabinus to Win 'Most Popular Comedian'". Nigerian Entertainment Today. Retrieved 5 July 2022.