Tafawa Balewa Square, (TBS) jẹ ilẹ ayẹyẹ ti o tó 35.8 acres (14.5 ha) (eyiti akoko npe ni “race course” ) ni Lagos Island, Lagos . [1] [2]

Tafawa Balewa Square Image

Race course ti ipinle Èkó(tí a ti yí oruko rè padà sí Tafawa Balewa Square jé pápá ìseré fún ìdíje ere elesin, sùgbón tí o ní aye fún boolu afese gbá àti eré idaraya cricket. Oba Dosunmu ni o fi Ilè náà fún àwon ìjoba akonileru ní odun 1859. Sùgbón ìjoba Yakubu Gowon padà da ibè wo láti ko Tafawa Belewa Square. Ni odun 1960, a tún ipa rè ojú eré esin náà kó láti se ayeye ominira Nàìjirià.

Ibi tí o kalè sí

àtúnṣe

Tafawa Balewa Square(tí a kó ní odun 1972 kalè sí arin Awolowo Road, Cable Street, Force Road, Catholic Mission Street àti independence building.[3]

Àwon ìtókasí

àtúnṣe
  1. Kaye Whiteman (2013). Lagos: A Cultural and Literary History (Landscapes of the Imagination). 5. Andrews UK Limited. ISBN 978-1-908-4938-97. https://books.google.com/books?id=fcS_BAAAQBAJ&pg=PT192&dq=. 
  2. Peju Akande. "BUILDING THE LAGOS CENTRAL BUSINESS DISTRICT". Thisdaylive. Archived from the original on 18 May 2015. https://web.archive.org/web/20150518085721/http://www.thisdaylive.com/articles/building-the-lagos-central-business-district/198358/. 
  3. "Tafawa Balewa Square". 10times Venues. January 13, 2018. Retrieved September 10, 2022.