Taiwo Abioye
Taiwo Olubunmi Abioye jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Englisi ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ láti di Ìgbàkejì adarí Covenant University.[1]
Taiwo Abioye | |
---|---|
Ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmò Englisi ní Covenant University | |
In office 2013–2016 | |
Ígbákejì adarí at Covenant University | |
In office 2012–2016 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kínní 1958 Ipinle Kaduna |
Residence | Canaanland, Ipinle Ogun |
Alma mater | Ahmadu Bello University (Bachelor of Education in Language Arts) Ahmadu Bello University ( Master of Arts in English) Ahmadu Bello University (Doctor of Philosophy in English) |
Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeA bí Taiwo ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gún oṣù kínní ọdun 1958, ní Kaduna sínú ìdílé àwọn òbí tó wá láti Ìpínlẹ̀ Ogun, Abioye gba àmì-ẹ̀yẹ àkọ́kọ́ nínú ìmò Language Arts Yunifásítì Àmọ́dù Béllò. Bákan náà ẹ̀wẹ̀, ó tẹ̀síwájú láti gba àmì-ẹ̀yẹ Master àti ti Dókítá ní ilé-ìwé kan náà ní ọdun 1992 àti 2004.[2] Ní ọdun 1982, Abioye gba àmì-ẹ̀yẹ akẹ́kọ̀ọ́ tó mọ̀wé jùlọ ni ẹ̀ka Inglisi ti Yunifásitì Àmọ́dù Béllò.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Oyedepo urges FG to Increase funding to education". World Stage. January 18, 2018. Archived from the original on 2018-01-30. Retrieved 2018-01-30.
- ↑ admin (2017-11-22). "Taiwo Abioye" (PDF). covenantuniversity.edu.ng. Retrieved 2017-11-22.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ admin. "Prof Taiwo Olubunmi Abioye". covenantuniversity.edu.ng. Archived from the original on 2017-09-24. Retrieved 2017-11-23.