Teddy Pendergrass
Theodore DeReese "Teddy" Pendergrass, Sr. (March 26, 1950[1] – January 13, 2010[2]) je akorin R&B/soul ara Amerika. Pendergrass koko gbajumo gege bi akorin asiwaju egbe olorin Harold Melvin & the Blue Notes ninu awon odun 1970 koto bere sini da korin nipari ewadun na. Ni odun 1982 o ni ipalara gidi leyin ijamba oko ni Philadelphia eyi fa iyaro re lati ibadi de sale.
Teddy Pendergrass | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Theodore DeReese Pendergrass |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Philadelphia, Pennsylvania, USA |
Irú orin | R&B, soul, gospel, jazz |
Occupation(s) | Singer, songwriter, composer |
Instruments | Vocals, piano, guitar, drums |
Years active | 1970–2006 |
Labels | Philadelphia International Asylum Elektra Surefire/Wind Up |
Associated acts | Harold Melvin & The Blue Notes |
Website | Official site |
Igba ewe
àtúnṣeO je bibi gege bi Theodore DeReese Pendergrass ni Kingstree, South Carolina ni Amerika, omo Jesse Pendergrass ati Ida Geraldine Epps. Nigba ewe Pendergrass, baba re fi ebi re sile ko to ku ni 1962. Lodun melo leyin eyi ni won ko lo si Philadelphia ibi ti Theodore to lo si Thomas Edison High School for Boys. O je omo egbe akorin Edison Mastersingers. Leyin eyi lo fi ile-eko sile[3] fun ise orin. Gege bi olukowe Robert Ewell Greene se so Pendergrass di alufa nigba ewe re. Ko pe sigba yi lodi onilu ati akorin fun egbe akorin.
Ise orin
àtúnṣePendergrass bere ise orin gege ni onilu fun The Cadillacs ki won o to darapo mo Harold Melvin & the Blue Notes. Nigbati Pendergrass fi egbe akorin Harold Melvin & the Blue Notes sile leyin ijiyan pelu Harold Melvin, o bere si ni dakorin o si gbe awo-orin bi "The More I Get the More I Want," "Close the Door," "I Don't Love You Anymore," "Turn Off the Lights" ati awon miran jade.[1]
Awo-orin to koko da gbejade ni akole Teddy Pendergrass (1977), eyi to tele ni Life is a Song Worth Singing (1978), Live Coast to Coast ati Teddy (1979), TP (1980) ati It's Time for Love (1981).[1] O tun korin pelu Whitney Houston ninu orin "Hold Me" lati awo-orin Houston.
Awon awo-orin
àtúnṣe- 1977: Teddy Pendergrass
- 1978: Life Is a Song Worth Singing
- 1979: Teddy
- 1980: TP
- 1981: It's Time for Love
- 1982: This One's for You
- 1983: Heaven Only Knows
- 1984: Love Language
- 1985: Workin' It Back
- 1988: Joy
- 1991: Truly Blessed
- 1993: A Little More Magic
- 1997: You and I
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 allmusic Biography
- ↑ WALTERS, PATRICK (January 13, 2010). "Soul Singer Teddy Pendergrass Dies in Pa. at 59". ABC News (Philadelphia, Pennsylvania: Associated Press). http://abcnews.go.com/Entertainment/wireStory?id=9557397. Retrieved 14 January 2010.
- ↑ "Singer fights his way back after accident". Anchorage Daily News. July 7, 1984. http://news.google.ca/newspapers?id=Nf0jAAAAIBAJ&sjid=iacEAAAAIBAJ&pg=1271,3392372&dq=teddy-pendergrass+dropout&hl=en. Retrieved January 6, 2010.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]