Temie Giwa-Tunbosun
Temie Giwa-Tubosun ( wọ́n bí Olúwalòní Olámìídé Gíwá ní Oṣù Kejìlá ọdún 1985) Ó jẹ́ Alàkóso ìlera Nàìjíríà-Amẹ́ríkà , òun sì ni Olùdásílẹ̀ LifeBank (tí orúkọ rẹ̀ tẹ́lẹ̀ ń jẹ́ One Percent Project), ilé-iṣẹ́ tó wà ní Nàìjíríà tó ń ṣiṣẹ́ lórí láti fi ẹ̀jẹ̀ tó dára láti ara ẹnìkan sí ẹlòmíràn ní ìlú.[1][2][3][4]
Temie Giwa | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Olúwalóní Ọlámidé Gíwá Oṣù Kejìlá 1985 Ila Orangun, Osun, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian, American |
Orúkọ míràn | Temie Giwa, Temie Giwa-Tubosun |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Minnesota State University Moorhead, Middlebury Institute of International Studies at Monterey |
Iṣẹ́ | Health Entrepreneur |
Olólùfẹ́ | Kola Tubosun |
Website | lifebank.ng |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Blood shortage a huge problem in Nigeria". The Nation. 8 April 2016.
- ↑ "For One Percent: An Innovative Blood Bank in Nigeria". Nigerian Health Watch. 25 August 2015.
- ↑ "How innovative Mobile App is saving lives by connecting blood donors & recipients". Nigerian Health Watch. 28 August 2015. Archived from the original on 24 April 2016. Retrieved 31 July 2022.
- ↑ "Temie wins Netpreneur award". TheAfricanDream.net. 17 November 2019.