Teni (olórin)

Akọrin obìnrin

Teniola Apata, tí a bí ní 23 Oṣù kejìlá ọdún 1992, tí a mọ̀ sí Teni, jẹ́ akọrin ati amúlúdún ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[3][4][5]

Teni
Teni ń bá Wazobia Max TV sọ̀rọ̀ ní oṣù keje ọdún 2018
Teni ń bá Wazobia Max TV sọ̀rọ̀ ní oṣù keje ọdún 2018
Background information
Orúkọ àbísọTeniola Apata[1]
Ọjọ́ìbí23 December 1992
Lagos State, Nigeria
Irú orinAfro
Occupation(s)
 • Singer
 • songwriter
 • entertainer
InstrumentsVocals
Years activeọdún 2016 di àkókò yìí
LabelsDr. Dolor Entertainment
Associated acts

Ìgbésí ayé àti ìbẹ̀rẹ̀ orin rẹ̀

àtúnṣe

A bí Teni ní 23 Oṣù kejìlá ọdún 1992, ni ìpínlẹ̀ Èkó. Ó jẹ́ àbúrò olórin ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí à ń pè ní Niniola . [6]

Ó kàwé ni lé ìwé gírámà Apata Memorial High School. Ó sì kàwé ni ilé ìwé gíga America Intercontinental University níbi tí ó ti gboyè nínú imọ ìṣàkóso ìṣòwò iṣowo. [7]

2016-2019: Fargin, Askamaya ati Awọn igbasilẹ miiran

àtúnṣe

Orin tí Teni kọ́kọ́ kọ ní "Amen" nígbà tí ó wà ní ìgbà ti Shizzi ń ṣe àkọ́so rẹ lábẹ́ rẹ́kọ́ọ̀dù "Magic Fingers Record". Ó kúrò nibẹ lọ sí Doctor Dolor ní ọdún 2017. [8]

Òkìkí rẹ bẹ̀rẹ̀ sí ní gbòòrò lẹ́yìn tí ó kọ “Fargin” ní oṣù Kẹ̀sán ọdún 2017. Ìlú sì mọ ọkà lẹ́yìn tí ó kọ "Askaya", "case" àti "Uyo meyo"

Askamaya wà ní ipò karun dínlógún ní àwọn orin ogún tí wọ́n yà sọ́tọ̀ ní MTV Base,ti ó jẹ́ orin tí wọ́n nifẹ sí jùlọ ní ọdún 2018.

Àwọn amàṣàjọ orin rẹ̀ kookan

àtúnṣe
As lead artist
Ọdún tí ó kọ wọ́n Àkọlé Alúbọ́ọ̀mù
2016 "Amen" Non-album single
2017 "Fargin"
2018 "Wait"
"Pareke"
"Lagos"
"Askamaya"
"Fake Jersey"
"Shake Am"
"Case"
"Pray"
"Uyo Meyo"
2019 "Party Next Door" TBA
"Sugar Mummy"
"Power Rangers"
2020 "Marry" Non-album single
2021 "For You" ft Davido Wondaland
2021 "Dorime" Non-album single
As featured artist
Year Title Album
2018 "Rambo" (Dr. Dolor featuring Teni) Non-album single
"Pray"
"Aye Kan" (Shizzi featuring Teni and Mayorkun)
2019 "Sound" (Diamond Platnumz feat. Teni) Non-album single
2020 Fuji Pop (Ojayy Wright featuring Teni) Non-album single
Writing credits
Year Title Album
2017 "Like Dat" by Davido Non-album single

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe

[Ẹ̀ka:Àwọn ọmọ Yorùbá]]

 1. Anazia, Daniel (February 29, 2020). "Teni’s Billionaire concert at Indigo O2 Arena made London standstill". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved May 29, 2022. 
 2. "Teni and im former label boss Shizzi do gbas-gbos ontop mata of her hit song 'Case' - BBC News Pidgin". BBC News Pidgin. December 19, 2021. Retrieved May 29, 2022. 
 3. Bassey, Ekaete (May 4, 2022). "Teni lambasts critics dictacting how to spend her money - The Nation Newspaper". The Nation Newspaper. Retrieved May 29, 2022. 
 4. Kochhar, Nazuk (18 October 2018). "Teni rules, here's the proof". The FADER. https://www.thefader.com/2018/10/18/teni-rules-askamaya-fake-jersey-african-pop. 
 5. Olatunbosun, Yinka (26 October 2018). "Teni Makanaki's Strides to Stardom". This Day. https://www.thisdaylive.com/index.php/2018/10/26/teni-makanakis-strides-to-stardom/. 
 6. "My love for Niniola stronger than music –Teni Entertainer" (in en-US). Punch Newspapers. https://punchng.com/my-love-for-niniola-stronger-than-music-teni-entertainer/. 
 7. "SPOTLIGHT: My late father will be proud that his legacy is untarnished, says Teni". The Cable. https://lifestyle.thecable.ng/spotlight-teniola-the-entertainer. 
 8. "Teni Entertainer is one of Nigeria's fastest rising musicians" (in en-US). Archived from the original on 2017-01-27. https://web.archive.org/web/20170127145508/https://www.pulse.ng/buzz/teni-entertainer-is-one-of-nigeria-s-fastest-rising-musicians-id6076858.html.