Terra Kulture
Terra Kulture jẹ ilé àwòrán ati aṣa ni ìpínlè Eko tí o sì ni ilé oúnje ninú rè. [1]
Idasile
àtúnṣeAgbẹjọro Naijiria Bolanle Austen-Peters ni o da Terra Kulture silẹ ni ọdun 2003. [2]
Ní arin ilé naa jẹ ile ounjẹ wà àti ile ti a un kó àwon iwe ati nkan aṣa sí pèlú ilé awon aworan iyebiye ní Naijiria, [3] ilé ìtàgé tún wà níbè, [4] ati awọn iwe ní èdè méta to gbajumo jù ni Nàìjíríà, Hausa, Ibo . àti Yorùbá .
Ni ipade odoodun, wón ma ún ta àwon aworan iyebiye [5]
Terra Arena
àtúnṣeTerra Kulture ṣe ifilọlẹ ilé itage re, Ó le gba ènìyàn 450, a si ún pe ibè ní Terra Kulture Arena, ti o wa ni olu-iṣẹ rẹ Tiamiyu, Savage Crescent, Victoria Island, ìpinlè Eko, Nàìjíríà.
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ Akeem Lasisi (31 October 2014). "Terra Kulture has organised over 200 exhibitions – Austen-Peters". Archived from the original on 29 November 2014. https://web.archive.org/web/20141129075254/http://www.punchng.com/entertainment/arts-life/terra-kulture-has-organised-over-200-exhibitions-austen-peters/. Retrieved 29 November 2014.
- ↑ Rita Ohai (2 November 2014). "Austen-Peters: Living for the love of art". BusinessDay. Archived from the original on 3 March 2016. https://web.archive.org/web/20160303233708/http://businessdayonline.com/2014/11/austen-peters-living-for-the-love-of-art/. Retrieved 10 November 2014.
- ↑ "The masters showcase class at Distinction 2". 10 December 2014. http://www.vanguardngr.com/2014/12/masters-showcase-class-distinction-2/. Retrieved 2 January 2014.
- ↑ "Terra Kulture: The One-Stop Nigerian Cultural Shop". 12 November 2014. Archived from the original on 3 January 2015. https://web.archive.org/web/20150103114658/http://pulse.ng/celebrities/terra-kulture-the-one-stop-nigerian-cultural-shop-id3267563.html. Retrieved 3 January 2015.
- ↑ "Art auction market looks up, makes N286.6m in 2013". 10 January 2014. Archived from the original on 11 January 2014. https://web.archive.org/web/20140111185514/http://businessdayonline.com/2014/01/art-auction-market-looks-up-makes-n286-6m-in-2013/#.VKhSo581jqA. Retrieved 3 January 2014.