The Governor (Fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà)
Gomina jẹ́ fíìmù Nàìjíríà ti ọdún 2016, tó dá lórí ìlú Savannah, èyí tí wọ́n ṣe ní ìlú Calaba àti Cross River. Ó jẹ́ fíìmù ajẹmọ́-ìṣẹ̀lú alápá mẹ́tàlá, èyí tí olùdarí rẹ̀ jẹ́ Ema Edosio, tí òǹkọ̀tàn sì jẹ́ Yinka Ogun, Tunde Babalola àti Debo Oluwatuminu, Mo Abudu ló sì gbé e jáde.[1][2]
Ìṣàfihàn
àtúnṣeÌṣàfihàn àḱkọ́ rẹ̀ jáde ní ọjọ́ 7 Julu, ọdún 2016 lórí DStv ní aago mẹ́sàn-án ìrọ̀lẹ́.[3]
Àwọn akópa
àtúnṣe- Caroline Chikezie bí i Angela Ochello[4]
- Samuel Abiola bí i Toju Ochello
- Jude Chukwuka bí i Chief Sobifa Thomson
- Kunle Coker gege bí i Alagba Briggs[5]
- Taiwo Obileye bí i Oloye Momo-Ali
- Bimbo Manuel bí i David Ochello
- Kachi Nnochiri bí i Ahmed Halo
- Oluwa Frank bí i Henry Duke
- Kelechi Udegbe bí i Paul
- Ani iyoho bí i Musa
- Edmond Enaibe bí i Friday Bello
Ìṣọníṣókí
àtúnṣeAngela Ochello tó jẹ́ igbá-kejì gómìnà Savannah bá ara rẹ̀ ní ìkoríta kòyé-mi-mọ́ lẹ́yìn tí gómìnà kú. Ó ní àǹfààní láti ṣe àkóso ìlú pẹ̀lú àtìlẹyìn olórí àwon òṣìṣẹ́ rẹ̀, lọ́nà tí kò fi pa ìgbéyàwó rẹ̀ lára.[6]
Ìgbàwọlé
àtúnṣeGẹ́gẹ́ bí àwọn olólùfẹ́ eré náà ṣe sọ, fíìmù 'The Governor' jẹ́ èyí tó kọ́ni lọ́gbọ́n. Coker ṣe àpejúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó yẹ kí gbogbo ènìyàn tó ń ronú láti wọ ẹgbẹ́ òṣèlú ó wò.politics.[7]
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀
àtúnṣe- The Offer
- The Signing
- The Announcement
- The Assertion
- The Strike
- The Compromise
- Siege
- Atoke Road
- To Catch a Monkey
- The Business of Politics
- Teo-Thirds
- Twilight
- End Games
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "From EbonyLife TV comes ‘The Governor’". The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-06-26. Archived from the original on 2022-08-02. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ Augoye, Jayne (2022-01-14). "Mo Abudu finally responds to critics of 'Chief Daddy 2'". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02.
- ↑ izuzu, chibumga (2016-06-23). "Watch 1st teaser for upcoming political drama". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ "The Governor is a Woman – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2022-08-02.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ BellaNaija.com. "EbonyLife TV’s New Political Drama Series ‘The Governor’ is Receiving Rave Reviews | Watch Episode 2 Tonight!". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02.
- ↑ "The Governor warms up to Nigerian audience". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-08-01. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ "The Governor unravels intrigues in corridors of political terrain". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-08-04. Retrieved 2022-08-02.