The Hard Case
The Hard Case jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè Britain tí ó jáde ní ọdún 1995. Guy Ritchie ni ó kọ fíìmù yìí tí ó sì tún darí rẹ̀. Àwọn akópa fíìmù yìí ni Darren Spencer tí ó ṣe The player, Benedick Bates tí ó ṣe player àti Wale Ọjọ́ tí ó ṣe gambler. Fíìmù ogún ìṣẹ́jú yìí gbéwọ̀n ju fíìmù Ritchie kan tí í ṣe Lock, Stock and Two Smoking Barrels.
The Hard Case | |
---|---|
Adarí | Guy Ritchie |
Olùgbékalẹ̀ | Nick Burgess-Jones |
Òǹkọ̀wé | Guy Ritchie |
Àwọn òṣèré | Darren Spencer Benedick Bates Wale Ojo |
Ìyàwòrán sinimá | Jan Pester |
Olóòtú | Matthew Glen |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Spidercom Films |
Déètì àgbéjáde | 1995 |
Àkókò | 20 minutes |
Orílẹ̀-èdè | United Kingdom |
Èdè | English |
Àwọn Akópa
àtúnṣe- Darren Spencer bíi The player
- Benedick Bates bíi a Player
- Wale Ojo bíi The Gambler[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ The Hard Case, retrieved 2018-11-04